16 Encantaciones Relacionadas Con Egbe
16 Encantaciones Relacionadas Con Egbe
16 Encantaciones Relacionadas Con Egbe
(1)
Para evitar la muerte
Ogbè Òṣé
Ogbè sè rè ní ṣeke
A d’ífá fún akinlàwọn
Ẹyi ti egbe aye n ranni pè
Ti t run n ranni si
Ẹbọ ní w n ní kó ṣe
O gbẹbọ nibè ó rùbo
Nje, orí akinlàwọn dí ọtá
Ogbè sè rè ní ṣeke
Ẹbọ
Orúkọ kán
Alabahun méjì
Igbin mẹfa
Gbogbo tenu jẹ
Agbon méjì
Ẹyẹ etu méjì
En español
Ogbè sè rè ní ṣeke
Hicieron adivinación para akinlàwọn
A quien la Fraternidad estaba enviando a la tierra
Y la gente lo estaba llamando
Le dijeron que hiciera sacrificio
Y obedeció
Por eso, el destino de akinlàwọn
Es el de convertirse en una bala
Ogbè sè rè se ha convertido en ṣeke
Ifa dice que hay bendiciones de larga vida para usted y dice
que usted debe ofrecer sacrificio para que usted no muera de
manera inesperada o para que tenga cualquier accidente que
acorte su vida. Ifá dice que usted debe adorar a su Egbe de
manera muy piadosa y ofrecer a su Orí todo aquello que le
pida para que nada trabaje o resulte en contra suya. Ifá dice
que haga sacrificio y que siempre estime mucho los consejos
que le den sus ancestros.
Sacrificio
1 chivo
2 jicoteas
6 babosas
Todos los alimentos que pueda conseguir
2 cocos
2 Gallinas Guinea
Historia
Ẹbọ
Eyele fúnfún merin
Ẹyẹ etu méjì
3p l p ekuru fúnfún
3p l p ogede ominni
Ẹyin adirẹ ibile mẹfa
Gbogbo tenu jẹ
En español
Sacrificio
4 palomas blancas
2 Gallinas Guinea
Muchas tortas de frijoles cocinadas sin aceite
Bastante banana (omini)
6 huevos de gallina
Todos los alimentos que pueda conseguir
Medicina
Se muelen hojas de aje, hojas de ela e insectos que
frecuentemente se encuentran en las hojas antes
mencionadas. Se mesclan después con jabón negro. Se echa
ìyèròsùn sobre el tablero para marcar el signo y rezar la
encantación. Después de rezar, el ìyèròsùn se echa sobre los
materiales anteriores y se usa para bañarse.
Historia
Ifá le dijo que había bendiciones de mucha riqueza para él. Ifá
le dijo que sería el responsable de muchos que en el confiarían
y dependían de él. Ifá le dijo que hiciera sacrificio para que
esas bendiciones lleguen lo más rápido posible. El sacerdote le
indicó el sacrificio que debía ofrecer.
(3)
Para vencer a los enemigos
Ògúndà iworí
Ògúndà ní kó lapo
Iworí ní kó lofa
Ofa kán soso iworí ní n ṣe apo yoro yoro
A d’ífá fún aluba ilé
Abu fún aluba ọdé
Ẹbọ ní w n ní kiw n ó ṣe
W n gbẹbọ nibè w n rùbo
Nje ati aluba ilé
Ati aluba ọdé
Egbe mi ní yíò lẹ aluba wogbo
Ẹbọ
Orúkọ kán
Abo adirẹ méjì
Àkùkò adirẹ méjì
Gbogbo tenu jẹ
3p l p ekuru
Fitila méjì
Ẹpọ pùpá
En español
Sacrificio
1 chivo
2 gallinas
2 gallos
Todos los alimentos que pueda conseguir
Bastantes frijoles cocinados sin aceite
2 lámparas
Aceite de palma
Historia
Ifá les dijo que había bendiciones para vencer las dificultades
y todo problema que tuviesen en medio de los demás. Ifá le
dijo que hiciera sacrificio para alejar el mal y las trabas que le
impedían el exito. El sacerdote le indicó el sacrificio que debía
ofrecer.
(4)
Para vencer a los enemigos
Odí Ìròsún
Idin ó sun
Idin ó wo
Apa kán sun ní oode
O fi onde ro orí
A d’ífá fún egbe aye
Abu fún ti ọdé run
Ẹbọ ní w n ní kiw n ó ṣe
W n gbẹbọ nibè w n rùbo
Nje, egbe aye m n te lo
Borokinni run ó ní jẹ ki taye ó te
Ẹbọ
Àkùkò adirẹ méjì
Efo tete
Gbogbo tenu jẹ
Kánhin kánhin ati Òṣé abuwe
Otí ati obi
Ìgbá eru nlá
Ipon (ìgbá ti w n ṣe ti sibi)
Osun ati efún pùpá
Aso fúnfún opa mewa
En español
Sacrificio
2 gallos
Hierbas de tete
Todos los alimentos que pueda conseguir
Una esponja y jabón
Ginebra y obi àbàtà
Una calabaza grande de cargar
1 ipon (un tipo de calabaza que parece una cuchara)
10 yardas de tela blanca
Historia
(5)
Para vencer a los enemigos
Irete Ìròsún
Ate ninu ilosun
Horo ninu folo
A d’ífá fún borokinni aye
Abu fún ti run
Ẹbọ ní w n ní kiw n ó ṣe
W n gbẹbọ nibè w n rùbo
Nje, egbe mi ẹ jowo ẹ jade wa
Ẹyin egbe oní saworo idé
Ẹbọ
Àkùkò adirẹ méjì
3p l p ekuru
Gbogbo tenu jẹ
Otí
Obi àbàtà mẹfa
Ẹpọ pùpá
En español
Historia
Ifá les dijo que había bendiciones de mucha fama y que serían
reconocidas en todas partes y ante todos. Ifá le dijo que
hiciera sacrificio que serían siempre bendecidas y que reciban
todo bien de riqueza y fortuna. El sacerdote le indicó el
sacrificio que debía ofrecer.
(6)
Para evitar la muerte
Ogbè Òṣé
Ase sì hin
Ase sì ohun
Ohun ní kíí jẹ ki omi koto ó kun ki ó to dele
Iyan Ogbè ṣe ó gbodo lemo
Oka Ogbè ṣe ó gbodo dí yaya
Eran Ogbè ṣe ó gbodo ní eegun
A d’ífá fún ṣèkètè pèere
Ẹyi ti n ṣe olorí egbe ní ọdé run
A d’ífá fún kinkin kin-in-rin
Ẹyi ti n ṣe onibode ol run
Ẹbọ ní w n kiw n ó ṣe
Sekete pèere nikán ní n be lẹyin ti n rùbo
Nje, kinkin kin-in-rin m pèmi m o
Apepa ní ẹ npè ẹni
Apepa ní ẹ npè ẹniyan
M n mu eku, eja, eye, eran boo run mi lowo
Kinkin kin-in-rin m pèmi m o
Apepa ní ẹ npè ẹni
Apepa ní ẹ npè ẹniyan
Ẹbọ
Àkùkò adirẹ méjì
Alabahun méjì
Igbin mẹfa
Eku méjì
Eja méjì
Abo adirẹ méjì
Ewuré kán
Obi àbàtà mejo
Otí
En español
Lo hicimos allí
Lo hicimos allí
Es el que no permite que el agua
Caiga para llenar el hueco
El que machuca el ñame de Ogbè Òṣé no es problemático
El que cocina la harina de ñame de Ogbè Òṣé no tiene ningún
problema
La carne de Ogbè Òṣé no puede tener hueso
Hicieron adivinación para ṣèkètè père
Que es la cabeza de la fraternidad celestial
Hicieron adivinación para kinkin kin-in-ni
Que es guardián de la puerta de entrada de los ancestros
Les dijeron que hiciera sacrificio
Y fue solo ṣèkètè père el que ofreció
Por eso, kinkin kin-in-rin, no me llames de nuevo
Es llamando a la muerte como tu llamas a alguien
Yo esto ofreciendo eku ifá, eja àro, pájaros y carne
Para alimentar a mis ancestros
Kinkin kin-in-rin, no me llames de nuevo
Es llamando a la muerte como tu llamas a alguien
Tú llamas a la muerte
Ifa dice que hay bendiciones de larga vida para usted. Ifá dice
que debe ofrecer sacrificio para que usted no muera de
manera inesperada o para que no tenga algún accidente que
acorte su vida. Ifá dice que hay signos de muerte a su
alrededor. Ifá dice que debe ofrecer sacrificios y propiciar a su
fraternidad celestial para que le libren de la muerte.
Sacrificio
2 gallos
2 jicoteas
6 babosas
2 eku ifá
2 eja àro
2 gallinas
1 chiva
8 obi àbàtà
Ginebra
Historia
(7)
Para vencer a los enemigos
3ṣé Ògúndà
Semolu om asawo
A d’ífá fún egbe aye
Abu fún ti run
Ẹbọ ní w n ní kiw n ó ṣe
W n gbẹbọ nibè w n rùbo
Nje, ojo ti m dá kíí pè o
Om asawo
Ose om omolu o
Om asawo
Igi ti m wi kíí jọ tan o
Om asawo
Ose ó m lu o
Om asawo
Aso ti m wi kíí gbò o
Om asawo
Owo ti m n na kíí tan o
Om asawo
Ose ó m lu o
Om asawo
Ẹbọ
Orúkọ kán
Igbin mẹfa
3p l p ekuru
Aso fúnfún
Otí
Obi àbàtà mẹfa
En español
Sacrificio
1 chivo
6 babosas
Bastantes frijoles cocinados sin aceite
Tela blanca
Ginebra
6 obi àbàtà
Historia
Tuwa tuwa ní m po
Emi ó m ẹni toni kin n tuwa
A d’ífá fún muhanm jimo
Ẹyi ti n ṣe olorí egbe ní ọdé run
Ìgbá ti n ti ọdé run bowa sì ilé aye
Ẹbọ ní w n ní ki ó ṣe
O gbẹbọ nibè ó rùbo
Nje, muhanm ji m pa ẹyẹ fúnwa wà o
Ẹbọ
Alabahun méjì
Igbin mejo
Àkùkò adirẹ méjì
Abo adirẹ méjì
Gbogbo tenu jẹ
Ẹyẹ etu méjì
3p l p ekuru
En español
Sacrificio
2 jicoteas
8 babosas
2 gallos
2 gallinas
Todos los alimentos que pueda conseguir
2 Gallinas Guinea
Muchas tortas de frijoles cocinadas sin aceite
Historia
Ẹbọ
Orúkọ kán
Ẹyẹ etu méjì
Agbon méjì
3p l p ekuru
3p l p otí
Gbogbo tenu jẹ
En español
Sacrificio
1 chivo
2 Gallinas Guinea
2 cocos
Muchas tortas de frijoles cocinadas sin aceite
Bastante ginebra
Todos los alimentos que pueda conseguir
Historia
(10)
Para tener salud
Iworí Ògúndà
Iworí ó bar in
Elegan ní ó si
Ohun ti a ṣe ti aye fi n yin ẹni
Ohun naa ní a n ṣe ti aye fi n buni
A d’ífá fún eleeko
Ẹyi ti n ṣe olorí egbe ìgbá iwase
Ìgbá ti n ṣe ogbogbo arun
Ti n ninra kaka alàì lẹ dide
Ẹbọ ní w n ní kó ṣe
O gbẹbọ nibè ó rùbo
Nje, ẹyin egbe run mi
Ẹ gbami
Ẹ gbami
Ẹ m m jẹ kin te
Ẹbọ
Orúkọ kán
Ogede agbaagba
Efo tete
Àkùkò adirẹ méjì
Alabahun méjì
Igbin mejo
En español
Iworí ó bà rin
Elegan ní ó si
En lo que podamos hacer la gente sanará pronto
Es también por lo que hacemos que la gente culpa a otros
Hicieron adivinación para eleeko
Que es el líder de la fraternidad más antigua
Cuando estaba muy enfermo
Y no podía ni pararse por sí mismo
Le dijeron que hiciera sacrificio
Y obedeció
Por eso, que mi fraternidad celestial escuche
Por favor, que me ayude
Por favor, que me asista
Por favor, que no me deje ser abochornado
Ifa dice que hay bendiciones de salud para usted y dice que
usted debe ofrecer sacrificio para las enfermedades que le
están perturbando se alejen y no pierda la vida. Ifá dice que
ahora es el tiempo de ofrecer sacrificios y adorar a su
fraternidad en el Cielo parta que no le falte a usted
bendiciones de salud y pueda vivir muchos años más.
Sacrificio
1 chivo
Plátanos (agbagba)
Hierbas de tete
2 gallos
2 jicoteas
8 babosas
Historia
Ẹbọ
Orúkọ kán
Gbogbo tenu jẹ
Abo adiere méjì
3p l p ekuru
Otí
Obi àbàtà mẹfa
Aso fúnfún
En español
Sacrificio
1 chivo
Todos los alimentos que pueda conseguir
2 gallinas
Muchas tortas de frijoles cocinadas sin aceite
Ginebra
6 obi àbàtà
Tela blanca
Historia
(12)
Para tener hijos
Ìrètè odi
Alujan obele
A d’ífá fún janjasa
Ẹyi ti n ṣe olorí egbe lode run
Ẹbọ ní w n ní kó ṣe
O gbẹbọ nibè ó rùbo
Èrò Ìpo
Èrò Òfà
@ wá bá ní jẹbutu rere
Nje, janjasa iwo lo dajo ere
Alujan obele
Ẹbọ
Ewuré kán
Eku méjì
Eja méjì
Obi àbàtà mẹfa
Gbogbo tenu jẹ
3p l p ekuru
Otí
En español
Aluja obele
Hicieron adivinación para janjasa
Que es el líder de la fraternidad del cielo
Le dijeron que hiciera sacrificio
Y obedeció
Pelegrinos de Ìpó
Pelegrinos de Òfà
Vengan a vernos en medio de muchas bendiciones
Por eso, janjasa tú eres el que escogió el día de la celebración
Alujan obele
Ifa dice que hay bendiciones de para tener hijos. Ifá dice que
usted debe ofrecer sacrificio para que sus hijos nazcan bien y
saludables. Ifá dice que si usted tiene hijos, los debe cuidar
bien y atenderlos como es debido, como si tuviera el cuidado
del mismo Olodumare. Ifá dice que sus hijos y su educación
son su responsabilidad ante los demás y ante Olodumare. Ifá
dice que haga sacrificio y los eduque correctamente.
Sacrificio
1 chiva
2 eku ifá
2 eja àro
6 obi àbàtà
Todos los alimentos que pueda conseguir
Muchas tortas de frijoles cocinadas sin aceite
Ginebra
Historia
Osa lu Ogbè n jo
Oromonjogbo laaro
Olom ayan akara kesu
A d’ífá fún ṣeewo
Ẹyi ti n ṣe olorí egbe lode run
Ẹbọ ní w n ní kó ṣe
O gbẹbọ nibè ó rùbo
Èrò Ìpo
Èrò Òfà
@ wá bá laiku kángidi
Nje, ṣeewo ó olorí egbe
Ao ri ṣeewo olorí egbe m
Seewo ó olorí egbe
Ẹbọ
Orúkọ kán
Alabahun méjì
Igbin mẹfa
Gbogbo tenu jẹ
3p l p ekuru
Aso fúnfún
Obi àbàtà mẹfa
Otí
En español
Ifa dice que hay bendiciones de larga vida para usted y dice
que usted debe ofrecer sacrificio para que sus días en a tierra
sean muchos y muera después de haber visto las bendiciones
de Ifá en su vida a través de sus hijos, su familia, su
prosperidad, su trabajo, etc.
Sacrificio
1 chivo
2 jicoteas
6 babosas
Todos los alimentos que pueda conseguir
Muchas tortas de frijoles cocinadas sin aceite
Tela blanca
6 obi àbàtà
Ginebra
Historia
(14)
Para tener hijos
Iworí Ògúndà
Oteere ilé n yo
Oteere ilé n yo
A d’ífá fún eleeko
Ẹyi ti n ṣe olorí egbe lode isalaye
Oteere ilé n yo
Oteere ilé n yo
A d’ífá fún eleeko
Ẹyi ti n ṣe olorí egbe lode isal run
Ẹbọ ní w n ní kó ṣe
O gbẹbọ nibè ó rùbo
Nje, eleko m fẹyin ti ó
Bi iyere bà so afẹyin ti igi oko
Eleko m fẹyin ti o
Nje, egbe m n n jo lode
Egbe n jo
E bawa wà egbe wà wa
Egbe n jo
Ẹbọ
Elede kán
Abo adirẹ méjì
Eku méjì
Eja méjì
Gbogbo tenu jẹ
3p l p ekuru
Obi àbàtà mẹfa
Otí
En español
Ifa dice que hay bendiciones para tener hijos para usted. Ifá
dice que usted se está quejando por no ser feliz y no estar
contenta. Ifá dice que sus hijos le traerán muchas felicidades a
usted. Ifá dice que adore a su fraternidad para que le ayude a
cumplir sus deseos.
Sacrificio
1 puerco
2 gallinas
2 eku ifá
2 eja àro
Todos los alimentos que pueda conseguir
Muchas tortas de frijoles cocinadas sin aceite
Obi àbàtà
Ginebra
Historia
(15)
Para vencer a los enemigos
Iworí Ògúndà
Ogbooro lowo
Agba lese
Apake mende ilu
Bayi kó loju ní ti afi n jẹ obi loja ede
A d’ífá fún ifatoki om aja ní wanu
Ẹyi ti w n ní kó bò egbe rè kole baa jẹ ìgbá ire laye
W n ní kom ṣe ohun ti àwọn egbe rè n fe toba aye
Ẹbọ ní w n ní kó ṣe
O gbẹbọ nibè ó rùbo
Nje emi n gbò ti egbe ó
Kegbe naa ó wà gbò temi
Emi n gbò tegbe
Ẹbọ
Àkùkò adirẹ méjì
Abo adirẹ méjì
Gbogbo tenu jẹ
3p l p ekuru
Obi àbàtà mẹfa
Otí.
En español
Ogboro es la mano
Aaba es la pierna
Apake m nde ilu
Así es como lucimos cuando estamos comiendo
Obi en el Mercado de ede
Hicieron adivinación para ifatoki el hijo del perro del cielo
Que le dijeron que alimentara a su fraternidad
Para que viva su vida con comodidad en la tierra
Le dijeron que hiciera sacrificio
Y obedeció
Por eso, siempre he estado atento a mi fraternidad
Mi fraternidad debe estar atenta de mí también
Siempre he estado atento a mi fraternidad
Sacrificio
2 gallos
2 gallinas
Todos los alimentos que pueda conseguir
Muchas tortas de frijoles cocinadas sin aceite
6 kola nut àbàtà
Ginebra
Historia
(16)
Para vencer a sus enemigos
Iworí otura
Iworí wotu
Kokoru ó han
A d’ífá fún eleeko
Ẹyi ti n ṣe olorí egbe lode lsalaye
Ẹbọ ní w n ní kó ṣe
O gbe bò nibè ó rùbo
Ije eleko wà gbami ó
Egbe m fẹyin ti ó
Eleko wà gbami.
Ẹbọ
Orúkọ kán
3p l p iyere
Gbogbo tenu jẹ
3p l p ekuru
Aso fúnfún
Otí
Obi àbàtà mẹfa
En español
Iworí wotu
Kokoro ó han
Hicieron adivinación para eleeko
Que es la fraternidad local
Le dijeron que hiciera sacrificio
Y obedeció
Por eso, eleko ven a asistirme
Yo confío en ti
Eleko, ven a asistirme
Sacrificio
1 chivo
Bastante iyere
Todos los alimentos que pueda conseguir
Bastante cooked on less beans cake
Tela blanca
Ginebra
6 obi àbàtà
Historia