Alastair Mackenzie: Ìyàtọ̀ láàrin àwọn àtúnyẹ̀wò
Àwọn àlẹ̀mọ́: VisualEditor Edit Check (references) activated Edit Check (references) declined (uncertain) |
|||
Ìlà 6: | Ìlà 6: | ||
== Iṣẹ́ rẹ̀ == |
== Iṣẹ́ rẹ̀ == |
||
Mackenzie ṣe èdá-ìtàn Archie MacDonald nínú eré-oníṣe ti BBC drama, tí àkọ́lé rè ń jẹ́ ''Monarch of the Glen''.<ref name="autogenerated1">{{cite web|url=http://news.scotsman.com/features/Why-Archie-abdicated.2645552.jp|title=Why Archie abdicated}}</ref> |
Mackenzie ṣe èdá-ìtàn Archie MacDonald nínú eré-oníṣe ti BBC drama, tí àkọ́lé rè ń jẹ́ ''Monarch of the Glen''.<ref name="autogenerated1">{{cite web|url=http://news.scotsman.com/features/Why-Archie-abdicated.2645552.jp|title=Why Archie abdicated}}</ref> |
||
== Ìgbésí ayé rẹ̀ == |
|||
Ìlú Islington ló ń gbé, pẹ̀lú ìyàwò rẹ̀, tó jẹ́ òṣèrébìnrin ti ilẹ̀ Scotland, tí orúkọ rẹ̀ ń jẹ́ Susan Vidler, tí wọ́n sì jọ bí ọmọ méjì, ọmọbìnrin kan Martha, tí wọ́n bí ní oṣù kejìlá ọdún 1999, àti ọmọkùnrin kan, Freddie, tí wọ́n bí ní oṣù kẹsàn-án ọdún 2004.<ref name="autogenerated12" /><ref>{{cite web|url=http://www.scotsman.com/features/Interview-David-and-Alastair-Mackenzie.6842335.jp?articlepage=2|title=Interview: David and Alastair Mackenzie, film director and actor/screenplay writer - Scotsman.com<!-- Bot generated title -->}}{{Dead link|date=October 2018|bot=InternetArchiveBot|fix-attempted=yes}}</ref><ref>{{cite web|url=http://news.scotsman.com/tvradio/Laird-in-the-city.3350581.jp|title=Laird in the city}}</ref> |
|||
Ẹ̀gbọ́n rẹ̀ ni [[David Mackenzie (director)|David Mackenzie]], tó jẹ́ olùdarí fíìmù àti ọ̀kan lára àwọn olùásílẹ̀ ilé-iṣẹ́ Sigma Films. |
|||
== Àwọn ìtọ́kasí == |
== Àwọn ìtọ́kasí == |
Àtúnyẹ̀wò ní 06:28, 16 Oṣù Igbe 2024
Alastair Mackenzie | |
---|---|
Ọjọ́ìbí | 8 Oṣù Kejì 1970 Trinafour, Scotland |
Olólùfẹ́ | Susan Vidler |
Àwọn ọmọ | 2 |
Àwọn olùbátan | David Mackenzie (brother) |
Alastair Mackenzie (tí wọ́n bí ní ọjọ́ kẹjọ oṣù kejì, ọdún 1970) jẹ́ òṣèrékùnrin ilẹ̀ Scotland àti òǹkọ̀wé.
Ìbẹ̀rẹ̀pẹ̀pẹ̀ ayé rẹ̀
Wọ́n bí Alastair Mackenzie sí ìlú Trinafour, ní tòsí Perth, ó sì kàwé ní Westbourne House School àti Glenalmond College ní Perthshire.[1] Ó kúrò nílẹ̀ nígbà tí ó wà ní ọmọdún méjìdínlógún, ó sì lọ sí ìlú London.
Iṣẹ́ rẹ̀
Mackenzie ṣe èdá-ìtàn Archie MacDonald nínú eré-oníṣe ti BBC drama, tí àkọ́lé rè ń jẹ́ Monarch of the Glen.[2]
Ìgbésí ayé rẹ̀
Ìlú Islington ló ń gbé, pẹ̀lú ìyàwò rẹ̀, tó jẹ́ òṣèrébìnrin ti ilẹ̀ Scotland, tí orúkọ rẹ̀ ń jẹ́ Susan Vidler, tí wọ́n sì jọ bí ọmọ méjì, ọmọbìnrin kan Martha, tí wọ́n bí ní oṣù kejìlá ọdún 1999, àti ọmọkùnrin kan, Freddie, tí wọ́n bí ní oṣù kẹsàn-án ọdún 2004.[3][4][5]
Ẹ̀gbọ́n rẹ̀ ni David Mackenzie, tó jẹ́ olùdarí fíìmù àti ọ̀kan lára àwọn olùásílẹ̀ ilé-iṣẹ́ Sigma Films.
Àwọn ìtọ́kasí
- ↑ "Borgen's Alastair Mackenzie on his TV comeback". The Scotsman. 8 January 2015. Retrieved 8 January 2015.
- ↑ "Why Archie abdicated".
- ↑ Àṣìṣe ìtọ́kasí: Invalid
<ref>
tag; no text was provided for refs namedautogenerated12
- ↑ "Interview: David and Alastair Mackenzie, film director and actor/screenplay writer - Scotsman.com".[Ìjápọ̀ tí kò ṣiṣẹ́ mọ́]
- ↑ "Laird in the city".