Jump to content

Bàlúṣì: Ìyàtọ̀ láàrin àwọn àtúnyẹ̀wò

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Content deleted Content added
Addbot (ọ̀rọ̀ | àfikún)
k Bot: Migrating 38 interwiki links, now provided by Wikidata on d:q201501 (translate me)
Rescuing 1 sources and tagging 0 as dead.) #IABot (v2.0.9.5
 
(Àwọn àtúnyẹ̀wò inú àrin 5 látọwọ́ àwọn oníṣe kò hàn)
Ìlà 1: Ìlà 1:
[[Bàlúsì tàbí Bàlósì]]
[[Bàlúṣì tàbí Bàlóṣì]]


[[Baluchi or Balochi]]
[[Baluchi or Balochi]]


Omo egbé èdè tí a ń pé ní Iranian ni Bàlúsì. Àwon tí ó ń so ó tó mílíònù márùn-ún. Púpò nínú àwon tí ó ń so ó yìí ni ó wà ní Pakísítáánì (Pakistan) ní Bàlúsísítáànì (Baluchistan). Baluclistan yìí ni ìpínlè (province) tí ó wà ní apá ìwò-oòrùn jùní pakcstan. Àwon tí ó ń so èdè yìí ní Baluchistan tó múlíònù (Iran), Afuganíísítáànù (Afghanistan) àti In-índíà (India). Àkotó Lárúbáwá (Arabic) ni wón fi ko ó sílè. Àjo kan wà tí wón ń pè ní Baluchi Academy tí ó ń ń sí pé àkosílè èdè yìí páye.
Ọmọ ẹgbẹ́ èdè tí a ń pé ní Iranian ni Bàlúṣì. Àwọn tí ó ń sọ ọ́ tọ́ mílíọ̀nù márùn-ún. Púpọ̀ nínú àwọn tí ó ń sọ ọ́ yìí ni ó wà ní Pakísítáánì (Pakistan) ní Bàlúṣísítáànì (Baluchistan). Baluclistan yìí ni ìpínlẹ̀ (province) tí ó wà ní apá ìwọ̀-oòrùn jùní pakcstan. Àwọn tí ó ń sọ èdè yìí ní Baluchistan tó múlíọ̀nù (Iran), Afuganíísítáànù (Afghanistan) àti In-índíà (India). Àkọtọ́ Lárúbáwá (Arabic) ni wọ́n fi kọ ọ́ sílẹ̀. Àjọ kan wà tí wọ́n ń pè ní Baluchi Academy tí ó ń ń sí pé àkọsílẹ̀ èdè yìí páye.<ref name="Omniglot 2019">{{cite web | title=Baluchi language, alphabet and pronunciation | website=Omniglot | date=2019-06-16 | url=https://www.omniglot.com/writing/baluchi.php | access-date=2019-11-20}}</ref> <ref name="Institutionen för lingvistik och filologi 2019">{{cite web | title=The Balochi Language Project - Uppsala universitet | website=Institutionen för lingvistik och filologi | date=2019-11-15 | url=https://www.lingfil.uu.se/forskning/the-balochi-language-project/ | access-date=2019-11-20 | archive-date=2019-08-25 | archive-url=https://web.archive.org/web/20190825044610/http://www.lingfil.uu.se/forskning/the-balochi-language-project/ | dead-url=yes }}</ref>

==Àwọn Ìtọ́kasí==
{{Reflist}}

Àtúnyẹ̀wò lọ́wọ́lọ́wọ́ ní 21:09, 9 Oṣù Ẹ̀bìbì 2024

Bàlúṣì tàbí Bàlóṣì

Baluchi or Balochi

Ọmọ ẹgbẹ́ èdè tí a ń pé ní Iranian ni Bàlúṣì. Àwọn tí ó ń sọ ọ́ tọ́ mílíọ̀nù márùn-ún. Púpọ̀ nínú àwọn tí ó ń sọ ọ́ yìí ni ó wà ní Pakísítáánì (Pakistan) ní Bàlúṣísítáànì (Baluchistan). Baluclistan yìí ni ìpínlẹ̀ (province) tí ó wà ní apá ìwọ̀-oòrùn jùní pakcstan. Àwọn tí ó ń sọ èdè yìí ní Baluchistan tó múlíọ̀nù (Iran), Afuganíísítáànù (Afghanistan) àti In-índíà (India). Àkọtọ́ Lárúbáwá (Arabic) ni wọ́n fi kọ ọ́ sílẹ̀. Àjọ kan wà tí wọ́n ń pè ní Baluchi Academy tí ó ń ń sí pé àkọsílẹ̀ èdè yìí páye.[1] [2]

Àwọn Ìtọ́kasí

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]
  1. "Baluchi language, alphabet and pronunciation". Omniglot. 2019-06-16. Retrieved 2019-11-20. 
  2. "The Balochi Language Project - Uppsala universitet". Institutionen för lingvistik och filologi. 2019-11-15. Archived from the original on 2019-08-25. Retrieved 2019-11-20.