Jump to content

Lateef Adedimeji: Ìyàtọ̀ láàrin àwọn àtúnyẹ̀wò

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Content deleted Content added
k Ọmọladéabídèmí99 ṣeyípòdà ojúewé Lateef AdedimejìLateef Adedimeji
No edit summary
Ìlà 1: Ìlà 1:
{{short description|Nigerian actor }}
'''{{PAGENAME}}''' (tí wọ́n bí ní Ọjọ́ kìíní oṣù kejì ọdún 1986) jẹ́ gbajúmọ̀ òṣèré, oǹkọ̀tàn àti olóòtú sinimá àgbéléwò ọmọ bíbí [[ìpínlẹ̀ Ògùn]] ṣùgbọ́n tí wọ́n bí sí [[ìpínlẹ̀ Èkó]] lórílẹ̀ èdè [[Nàìjíríà]]. Lọ́dún 2013 ni ìràwọ̀ rẹ̀ gbòde kan lẹ́yìn látàrí ipa tí ó kó nínú sinimá àgbéléwò kan tí àkọ́lé rẹ̀ ń jẹ́ "Kudi Klepto", tí Yéwándé Adékọ̀yà ṣe agbátẹrù rẹ̀. {{PAGENAME}} tí kópa nínú sinimá àgbéléwò tí ó ti ju ọgọ́rùn-ún lọ lẹ́yìn tí ó ti bẹ̀rẹ̀ iṣẹ́ sinimá àgbéléwò lọ́dún mẹ́ẹ̀ẹ́dógún sẹ́yìn. Ó gbajúmọ̀ tó bẹ́ẹ̀ gẹ́ tí ilé iṣẹ́ ìbánisọ̀rọ̀ Airtel fi fi í ṣe aṣojú wọn.<ref name="Google Search">{{cite web | title=lateef adedimeji | website=Google Search | url=https://www.google.com/search?q=lateef+adedimeji&oq=lateef+&aqs=chrome.1.69i57j0l3j69i60.3729j0j4&client=ms-android-meizu&sourceid=chrome-mobile&ie=UTF-8 | access-date=2019-12-07}}</ref> <ref name="Tribune Online 2019">{{cite web | title=I was once paid N4,000 for lead role - Lateef Adedimeji » Tribune Online | website=Tribune Online | date=2019-09-08 | url=https://tribuneonlineng.com/i-was-once-paid-n4000-for-lead-role-lateef-adedimeji/ | access-date=2019-12-07}}</ref>
{{Unreliable sources|date=October 2019}}
{{Use dmy dates|date=November 2021}}
{{Infobox actor
| name = Lateef Adedimeji
| image = Lateef Adedimeji at AMA Award 30.jpg
| image_size =
| height =
| alt =
| caption = Adedimeji at AMAA 2021
| birth_name = Abdullateef Adetola Adedimeji
| birth_date = {{Birth date and age|df=yes|1984|2|1}}
| birth_place = Isolo, [[Lagos State]], Nigeria
| other_names = "Crying Machine"<ref name="theinfopro.com.ng">{{cite web|title=Lateef Adedimeji Biography and Net Worth 2019|url=https://theinfopro.com.ng/lateef-adedimeji-biography-net-worth-wikipedia/}}</ref>
| occupation = {{flatlist|
* Renowned Actor
*filmmaker
}}
| known for = Kudi Klepto
| spouse = {{marriage|[[Oyebade Adebimpe]]|2021}}
| parents =
| citizenship = Nigerian
| relatives =
| years_active = 2007–present
| alma_mater = [[Olabisi Onabanjo University]]
| known_for = Acting
| awards = {{bulleted list
| 2018 Best of Nollywood Awards—Best Actor in a Lead Role (Yoruba)}}
| website =
}}
'''Adetola Abdullateef Adedimeji''' {{Audio|Yo-Adetola Abdulateef Adedimeji.ogg|Listen|help=no}} (wọ́n bí i ní February 1, 1984) ó jẹ́ ọmọ orílẹ́-èdè [[Nigerian]] [[òṣèré]] àti [[Agbéréjáde]]. <ref name=":1">{{Cite web|last=The360reporters|date=18 July 2021|title=Lateef Adedimeji Net Worth: Lateef Adedimeji Biography, Age, Career And Net Worth.|url=https://the360report.com/lateef-adedimeji-net-worth-and-biography/|access-date=20 November 2021|website=The360Report|language=en-US}}</ref><ref>{{Cite web |date=2022-05-21 |title=Lateef Adedimeji: The more the fame, the more we need a lot of improvement |url=https://guardian.ng/saturday-magazine/lateef-adedimeji-the-more-the-fame-the-more-we-need-a-lot-of-improvement/ |access-date=2022-07-17 |website=The Guardian Nigeria News - Nigeria and World News |language=en-US}}</ref> Ọ̀pọ̀ ènìyàn ni wọ́n mọ̀ ọ́n fún ipa gbòógì rẹ̀ àkọ́kọ́ tí ó kó nínú eré Yéwándé ([[Yewande Adekoya]])'s ní ọdún 2013 èyí tí ó pe àkọlé rẹ̀ ní ''Kudi Klepto'' bẹ́ẹ̀ ni ó ti kó ipa takuntakun nínú àwọn eré tí wọ́n lé ní ọgọ́rùn-ún (100) <ref>{{Cite web|last=Mbuthia|first=Mercy|date=1 February 2021|title=Lateef Adedimeji biography: age, wife, children, net worth, songs|url=https://www.legit.ng/1399886-lateef-adedimeji-biography-age-wife-children-net-worth-songs.html|access-date=20 November 2021|website=Legit.ng – Nigeria news.|language=en}}</ref> Ó bẹ̀rẹ̀ sí ní kó ipa nínú eré orí ìtàgé àti àgbéléwò láti bí ọdún mẹ́ẹ̀dógún. Òun ni ó jẹ́ aṣojú ìpolówó [[brand ambassador]] fún ilé iṣẹ́ [[Airtel]] àti Numatville Megacity.<ref name="Afro23">{{cite web|url=https://afro23.com/blog/biography-and-net-worth-of-lateef-adedimeji/|title=Biography and net worth of Lateef Adedimeji}}</ref>


==Ìbẹ̀rẹ̀ pẹ̀pẹ̀ ayé rẹ̀==
{{Infobox person
| name = Lateef Adedimeji
| image = Lateef Adedimeji at AMA Award 30.jpg
| image_size =
| height =
| alt =
| caption =
| birth_name = Abdullateef Adedimeji
| birth_date = {{Birth date|df=yes|1986|02|1}}
| birth_place = Oshodi, [[Ìpínlẹ̀ Èkó]], Nàìjíríà
| other_names = "Crying Machine"
| nationality = [[Nàìjíríà]]
| citizenship = Nàìjíríà
| occupation = {{flatlist|
*Actor
*Filmmaker
*Scriptwriter
*Director
*Producer}}
| parents =
| relatives =
| years_active = 2007- Present
| known_for =
| website =
|alma mater=Yunifásítì Olabisi Onabanjo|spouse=Oyebade Adebimpe}}


Wọ́n bí Lateef Adedimeji ní ọjọ́ kì-ín-ní, oṣù kejì, ọdún 1984 ni agbegbe kan tí wọ́n ń pè ní Isolo, [[Lagos State]]. Ó jẹ́ ọmọ [[Abeokuta]], ní Ìpínlẹ̀ Ògùn [[Ogun State]].<ref name="theinfopro.com.ng"/>
==Ìgbé-ayé àti aáyan ìkẹ́kọ̀ọ́ rẹ̀==
Gẹ́gẹ́ bí a ti sọ ṣáájú, wọ́n bí Lateef Adédiméjì ní Ọjọ́ kìíní oṣù kejì ọdún 1986 ni ìpínlẹ̀ Èkó lórílẹ̀ èdè Nàìjíríà, ṣùgbọ́n ọmọ bíbí ìpínlẹ̀ Ògùn ni.<ref name="theinfopro.com.ng">{{cite web|url=https://theinfopro.com.ng/lateef-adedimeji-biography-net-worth-wikipedia/|title=Lateef Adedimeji Biography and Net Worth 2019|access-date=2019-12-07|archive-date=2019-10-06|archive-url=https://web.archive.org/web/20191006110819/https://theinfopro.com.ng/lateef-adedimeji-biography-net-worth-wikipedia/|dead-url=yes}}</ref> O kàwé gboyè dìgírì nínú ìmọ̀ ìwé ìròyìn, ni ifáfitì [[Yunifásítì Olabisi Onabanjo]].<ref>{{cite web|url=https://www.pulse.ng/entertainment/movies/7-emerging-yoruba-movie-stars-you-need-to-know/vtfplhw|title=7 emerging Yoruba movie stars you need to know|work=Pulse.ng}}</ref>


==Ètò ẹ̀kọ́ rẹ̀==


Lateef bẹ̀rẹ̀ ètò ẹ̀kọ́ rẹ̀ ní Ire Akari Primary School, Isolo, [[Lagos State]], bẹ́ẹ̀ ni ó lọ sí Ilamoye Grammar School Okota ní Ìpínlẹ̀ Èkó [[Lagos State]] fún ètò ẹ̀kọ́ girama. <ref name=":1" /> Bẹ́ẹ̀ ni ó kẹ́kọ̀ọ́ ní Onikan tí ó wà ní Ìpínlẹ̀ Èkó [[Lagos State]] níbi tí ó ti kẹ́kọ̀ọ́ nípa ìṣeré orí ìtàgé. <ref name=":1" /> Ẹ̀bùn ìkọ̀wé rẹ̀ àti bí a ṣe ń ṣeré orí ìtàgé gbèrú si lábẹ́ àjọ kan tí kìí ṣe ti ìjọba [[Non-governmental organization| Non-governmental organization (NGO)]] èyí tí orúkọ rẹ̀ ń jẹ́ (Community Life Project). <ref name=":1" /> Ó kẹ́kọ̀ọ́ gboyè ní ilé ẹ̀kọ́ [[Olabisi Onabanjo University]], níbi tí ó ti gba oyè ìjìnlẹ̀ àkọ́kọ́ [[bachelor's degree] nínú Mass Communication.<ref>{{cite web|url=https://www.pulse.ng/entertainment/movies/7-emerging-yoruba-movie-stars-you-need-to-know/vtfplhw|title=7 emerging Yoruba movie stars you need to know|work=Pulse.ng|date=16 April 2019}}</ref>
==Ìgbé ayé tí ara ẹni==
Ni ọjọ kejidinlogun oṣù Kejìlá ọdún, 2021, Adedimeji fẹ afesona re , [[Oyebade Adebimpe]] ni ìgbéyàwó tí ọ l'arin rìn.<ref>{{Cite web|url=https://www.bbc.com/pidgin/media-59712969.amp|title=See photos from actor Lateef Adedimeji wedding wit colleague Adebimpe Oyebade|date=18 December 2021}}</ref>


==Iṣẹ́ rẹ̀==


Lateef Adedimeji bẹ̀rẹ̀ sí ní kópa lórí ìtàgé láti ọdún 2007, ó bẹ̀rẹ̀ iṣẹ́ òòjọ́ rẹ̀ pẹ̀lú ijó jíjó, <ref name=":1" /> tí ó sì tún lọ ilé ẹ̀kọ́ tí a ti ń kọ́ nípa ijó jíjó. Ó jẹ́ òṣèré [[Actor]] tí ó ti kó ipa onírúurú lórí ìtàgé láti ìgbà tí ó ti wà ní ọmọ ọdún mẹ́ẹ̀dógún ṣùgbọ́n tí ó bẹ̀rẹ̀ sí ní ṣe eré ní ọdún 2007 nígbà tí ó dara pọ̀ mọ́ Orisun TV. Ó ṣiṣẹ́ gẹ́gẹ́ bíi atọ́kùn ètò ní ilé iṣẹ́ agbóhùngbójìjí ti Orísun TV, orúkọ ètò tí ó máa ń ṣe nípa à ń ṣe eré orí ìtàgé ni Sábàbí. Ní ìgbà tí ó wà ní ilé ẹ̀kọ́ gírámà, gẹ́gẹ́ bí ẹni tí ó ti ń ṣe eré orí ìtàgé, àwọn àjọ kan tí wọn kì í ṣe ti ìjọba yàn án gẹ́gẹ́ bíi aṣojú àti olúdánilẹ́kọ̀ọ́ lórí àìsàn kògbóògùn [[HIV/AIDS]] èyí tí ọ̀pọ̀ ènìyàn máa ń kó láti ara ìbálòpọ̀ akọ sí abo lọ́nà tí kò ní ìdáàbò bò. Iṣẹ́ Lateef Adedimeji ni láti kó ipa nínú eré tí ó máa dá àwọn ènìyàn lẹ́kọ̀ọ́ lórí àwọn ààrùn tí a le kó láti ara ìbálòpọ̀, àwọn ewu tó wà nínú kí á má tọ́jú ààrùn náà àti bí wọ́n ṣe le di ààrùn kògbóògùn, bẹ́ẹ̀ ni ó tún kópa nínú jíjẹ́ kí àwọn ènìyàn ó mọn ẹ̀tọ́ àti ojúṣe wọn lábẹ́ òfin. Lateef jẹ́ ẹnìkan tí ó tètè ṣe àwárí ara rẹ̀ nínú kíkópa nínú eré orí ìtàgé tí ó sì gbé ìgbésẹ̀ láti wọ ẹgbẹ́ àwọn òǹṣèré. Ó ti kó ipa onírúurú bẹ́ẹ̀ ni ó ti bá àwọn òṣèré jàǹkànjàǹkàn ṣe eré àgbéléwò papọ̀ láti ìgbà tí ó ti darapọ̀ mọ́ ẹgbẹ́ àwọn òṣèré tíátà. Ọ̀pọ̀ ni ó mọ̀ ọ́n fún ipa tí ó máa ń kó gẹ́gẹ́ bíi ẹni tí omi ẹkún kò jìnnà sí lójú. Ní ọdún 2016, ó gba àmì ẹ̀yẹ [[2016 Best of Nollywood Awards]] fún òṣèré tí ó léwájú jùlọ nínú eré Yorùbá. <ref>{{Cite web|url=https://quopedia.blogspot.com/2017/11/lateef-adedimeji.html |title=Lateef Adedimeji Biography|website=quopedia.blogspot.com }}</ref> In 2015, he was nominated for [[City People Entertainment Awards]] for the 2015 Most Promising Actor of the year. Ọ̀pọ̀ àwọn ènìyàn a tilẹ̀ máa ń pè é ní àbúrò òṣèré kùnrin n nì ẹni tí orúkọ rẹ̀ ń jẹ́ [[Ọ̀dúnladé Adékọ́lá]] ṣùgbọ́n èyí tí kò rí bẹ̀. Ẹ̀bùn ìkọ̀wé tí ó ní ti mú un bá àjọ àgbáyé [[UNICEF]] dá iṣẹ́ papọ̀ rí. <ref>{{Cite web |url=https://theinfopro.com.ng/lateef-adedimeji-biography-net-worth-wikipedia/|title=Lateef Adedimeji Biography and Network 2019 |website=theinfopro.com }}</ref> He was awarded the face of [[Nollywood]] male<ref>{{Cite web|title=Premium Times – Nigeria leading newspaper for news, investigations|url=https://premiumtimesng.com/|access-date=20 November 2021|language=en-GB}}</ref> during the ENigeria Newspaper Night of Honour on 30 October 2021.
== Iṣẹ ==

Lateef Adedimeji bẹrẹ sí ní se ere ori itage ni ọdún 2007,o sí bẹrẹ ìjọ pẹlu ,<ref name=":1" /> a gba sí ilé ìwé ìjọ. Lateef Adedimeji jẹ [[Actor]] and [[Screenwriter]]. Lateef Adedimeji o ti farahàn ni orisiirisii èrè ori itage lati ọmọ ọdún mẹdogun sùgbón o bẹrẹ èrè ni ọdún 2007 nígbàtí o fara hàn lori ero amohun maworan Orisun TV. O bẹrẹ èrè ori itage lati ile iwe akọbẹrẹ started a Yàn láti sójú NGO gẹgẹ bí olufihan àrùn kogboogun [[HIV/AIDS]] campaign. Ipá rẹ ní lati sọ nípa àìsàn tí ọ bẹ ninu ìbálòpọ̀ [[human rights]] làti má ṣe àwòrán. Awọn ololufẹ rẹ mọ gẹgẹ bí ẹni tó mú iṣẹ rẹ ní okunkundun. O ti ṣe àfihàn pẹlu oríṣiríṣi awọn àgba òṣèré. Ni ọdún 2016, o gba àmì ẹ̀yẹ [[2016 Best of Nollywood Awards]] fun eléré ti ọ da yangan julọ (Yoruba).<ref>{{Cite web|url=https://quopedia.blogspot.com/2017/11/lateef-adedimeji.html |title=Lateef Adedimeji Biography|website=quopedia.blogspot.com }}</ref> ni ọdún 2015,a ka mo ará awọn ti ọ yẹ ki o gba àmì ẹ̀yẹ [[City People Entertainment Awards]] fún eléré ọdún 2015. Lateef jẹ ẹni tí a má n gbe Gbagi fún [[Odunlade Adekola]] nitori won jọ ará wọn àti ìwùwà. O ni anfààní lati ṣiṣẹ pẹlú [[UNICEF]] nítori ìwé kíkọ .<ref>{{Cite web |url=https://theinfopro.com.ng/lateef-adedimeji-biography-net-worth-wikipedia/ |title=Lateef Adedimeji Biography and Network 2019 |website=theinfopro.com |access-date=2019-12-07 |archive-date=2019-10-06 |archive-url=https://web.archive.org/web/20191006110819/https://theinfopro.com.ng/lateef-adedimeji-biography-net-worth-wikipedia/ |dead-url=yes }}</ref> a fún ní àmì ẹ̀yẹ gẹ́gẹ́ bí ojú nollywood [[Nollywood]] male<ref>{{Cite web|title=Premium Times – Nigeria leading newspaper for news, investigations|url=https://premiumtimesng.com/|access-date=20 November 2021|language=en-GB}}</ref>during the ENigeria Newspaper Night of Honour on 30 October 2021.
==Ìgbésí ayé rẹ̀==
Ní ọjọ́ kejìdínlógún, 18 December 2021, Adedimeji gbé akẹgbẹ́ rẹ̀ níyàwó, ẹni tí òun náà jẹ́ òṣèré eré orí ìtàgé, [[Oyebade Adebimpe]] pẹ̀lú ìgbéyàwó alárinrin. <ref>{{Cite web|url=https://www.bbc.com/pidgin/media-59712969.amp|title=See photos from actor Lateef Adedimeji wedding wit colleague Adebimpe Oyebade|date=18 December 2021}}</ref><ref>{{Cite web |title=Lateef Adedimeji clinches international award - P.M. News |url=https://pmnewsnigeria.com/2022/06/07/lateef-adedimeji-clinches-international-award/ |access-date=2022-08-02 |language=en-US}}</ref>

==Àwọn eré tí ó ti kó ipa==

*'' Kudi Klepto '' (2015)
*'' Yeye Oge'' (2016)
*'' Once Upon a Time'' (2017)
*'' Ilu Ominira'' (2018)<ref>{{Cite web|title=Movies Featuring Lateef Adedimeji|url=https://ibakatv.com/lateef-oladimeji|website=ibakatv.com}}</ref>
*'' Bipolar (Àmódí)'' (2018)
*'' Bina Baku'' (2019)
*'' Depth'' (2019)
*'' Koto'' (2019)
*'' Igi Aladi'' (2019)
*'' Adebimpe Omooba'' (2019)
*[[Sugar Rush (film)|'' Sugar Rush (''2019)]] as Kpala
*'' Olokiki Oru'' (2019)
*''[[The New Patriots]]'' (2020) as Fred
*Rugudu (2020) as Chibuzor
*'' Veil'' (2020)
*''[[Soole]]'' (2021) as Julius
*Beauty and the Beast (2021)
*''[[Breaded Life]]'' (2021)<ref>{{Cite web|date=16 April 2021|title=New Nollywood comedy 'Breaded Life' hits cinemas|url=https://www.premiumtimesng.com/entertainment/nollywood/455641-new-nollywood-comedy-breaded-life-hits-cinemas.html|access-date=20 April 2021|language=en-GB}}</ref> as Jugunu
*''[[Dwindle (film)|Dwindle]]'' (2021)<ref>{{Cite web|last=Nwogu|first=Precious|date=3 June 2021|title=Check out the new teaser for Kayode Kasum & Dare Olaitan's 'Dwindle!'|url=https://www.pulse.ng/entertainment/movies/dwindle-movie-teaser/wryb9yr|access-date=10 June 2021|website=Pulse Nigeria|language=en}}</ref> as Fuku
*[[Ayinla (film)|'' Ayinla'']] (2021)<ref>{{Cite web|last=Nwogu|first=Precious|date=14 December 2020|title=Tunde Kelani announces production of Ayinla Omowura biopic titled 'Ayinla'|url=https://www.pulse.ng/entertainment/movies/tunde-kelani-announces-production-of-ayinla-omowura-biopic/xrew5p1|access-date=12 May 2021|website=Pulse Nigeria}}</ref> as Ayinla
*''[[Progressive Tailors Club]]'' (2021) as Saheed
*''[[Love Castle]]'' (2021) as Chi Joshua
*''[[A Naija Christmas]]'' (2021) as Tony Torpedo
*Prophetess (2021) as Ezekiel
*'' That One Time'' (2022)
*''[[King of Thieves (2022 film)]]'' (2022) as Abegunde
*'' Order of Things'' (2022) as Larry
*'' Strangers (2022'')<ref>{{Cite web |last=Nwogu |first=Precious 'Mamazeus' |date=2022-04-04 |title=Biodun Stephen's movie 'Strangers' based on true events set for April release |url=https://www.pulse.ng/entertainment/movies/biodun-stephens-movie-strangers-based-on-true-events-set-for-april-release/c9k7beh |access-date=2022-04-19 |website=Pulse Nigeria |language=en}}</ref>
*Romeo (2022) as Anjola
*Ojukoro (2022) as Bayo
*''[[Ile Alayo]]'' (2022)<ref name="Vanguard News 2022">{{cite web | title=Ile Alayo: Lateef Adedimeji leaves viewers amused in season 2 | website=Vanguard News | date=July 17, 2022 | url=https://www.vanguardngr.com/2022/07/ile-alayo-lateef-adedimeji-leaves-viewers-amused-in-season-2/ | access-date=July 29, 2022}}</ref>
*'' Different Strokes'' (2023) as Tade
*'' The Last Man Standing'' (2023)
*''[[Jagun Jagun]]'' (2023) as Gbotija
*''5 Billion Reasons'' (2023) as Maximus
*''Imade'' (2023) as Pastor
* ''[[She Must Be Obeyed]]'' (2023) as Bayo
* ''[[Hotel Labamba]] (2024)
* ''[[Anikulapo (Rise of Spectre)]]'' (2024) as Awolaran
* ''[[House of Ga'a]]'' (2024) as Lubu
* ''[[Lisabi: The Uprising]]'' (2024) as Lisabi Agbongbo Akala

==Àmì ẹ̀yẹ àti ìfidánilọ́lá==
{| class="wikitable"
!Year
!Award ceremony
!Prize
!Result
!Ref
|-
|2014
| rowspan="2" |Odua Movie Awards
| rowspan="2" |Best Actor
|{{won}}
| rowspan="2" |<ref>{{Cite web|title=Lateef Adedimeji: Biography, Career, Movies & More|date=24 May 2018 |url=https://nigerianfinder.com/lateef-adedimeji-biography-career-movies-more/}}</ref>
|-
| rowspan="3" |2015
|{{won}}
|-
|[[2015 Africa Magic Viewers Choice Awards|Best of Nollywood Awards]]
|Best Actor in a Lead Role (Yoruba)
|{{nom}}
|
|-
| rowspan="2" |[[City People Entertainment Awards]]
|Most Promising Actor of the Year (Yoruba)
|{{nom}}
|
|-
| rowspan="2" |2016
|Best Supporting Actor Of The Year (Yoruba)
|{{won}}
|
|-
|[[2016 Africa Magic Viewers Choice Awards|Best of Nollywood Awards]]
|Best Actor in a Lead Role (Yoruba)
|{{nom}}
|
|-
| rowspan="2" |2018
|[[2018 Best of Nollywood Awards|Best of Nollywood Awards]]
|Best Actor in a Lead Role (Yoruba)
|{{won}}
|<ref name=":0">{{Cite web|last=Augoye|first=Jayne|date=10 December 2018|title=BON Awards 2018: Tope Oshin, Tana Adelana win big|url=https://www.premiumtimesng.com/entertainment/nollywood/300174-bon-awards-2018-tope-oshin-tana-adelana-win-big.html|access-date=9 October 2021|language=en-GB}}</ref>
|-
|City People Movie Awards
|Best Actor Of The Year (Yoruba)
|{{nom}}
|
|-
| rowspan="2" |2019
| rowspan="2" |[[2019 Best of Nollywood Awards|Best of Nollywood Awards]]
|Best Actor in a Lead Role (Yoruba)
|{{nom}}
| rowspan="2" |<ref>{{Cite web|last=Bada|first=Gbenga|date=15 December 2019|title=BON Awards 2019: 'Gold Statue', Gabriel Afolayan win big at 11th edition|url=https://www.pulse.ng/entertainment/movies/bon-awards-2019-gold-statue-gabriel-afolayan-win-big-at-11th-edition/4d0w2n4|access-date=10 October 2021|website=Pulse Nigeria|language=en}}</ref>
|-
|Best Supporting Actor (Yoruba)
|{{won}}
|-
|2020
|[[2020 Best of Nollywood Awards]]
|Best Actor in a Lead role –Yoruba
|{{nom}}
|<ref>{{Cite web|date=12 December 2020|title=Behold hot steppers and winners at BON awards 2020|url=https://www.vanguardngr.com/2020/12/behold-hot-steppers-and-winners-at-bon-awards-2020/|access-date=11 October 2021|website=Vanguard News|language=en-US}}</ref>
|-
|2021
|[[17th Africa Movie Academy Awards|Africa Movie Academy Awards]]
|[[Africa Movie Academy Award for Best Actor in a Leading Role|Best Actor in a Leading Role]]
|{{nom}}
|<ref name=":02">{{Cite web|last=Banjo|first=Noah|date=29 October 2021|title=FULL LIST: Ayinla, Omo Ghetto: The Saga bag multiple nominations at AMAA 2021|url=https://punchng.com/full-list-ayinla-omo-ghetto-the-saga-bag-multiple-nominations-at-amaa-2021/|access-date=30 October 2021|website=Punch Newspapers|language=en-US}}</ref>
|-
|2022
|Hollywood and African Prestigious Awards (HAPA Awards)
|Best Actor in Africa
|{{Won}}
|<ref name="Online 2022">{{cite web | last=Online | first=Tribune | title=Nollywood actor Lateef Adedimeji bags international award | website=Tribune Online | date=June 7, 2022 | url=https://tribuneonlineng.com/nollywood-actor-lateef-adedimeji-bags-international-award/ | access-date=August 2, 2022}}</ref>
|}

== See also ==
*[[List of Yoruba people]]


==Àwọn Ìtọ́kasí==
==Àwọn Ìtọ́kasí==
{{Reflist}}
{{Reflist}}

{{Authority control}}


{{DEFAULTSORT:Adedimeji, Lateef}}
{{DEFAULTSORT:Adedimeji, Lateef}}
[[Category:Living people]]
[[Ẹ̀ka:Àwọn ọjọ́ìbí ní 1986]]
[[Category:1986 births]]
[[Ẹ̀ka:Àwọn ọmọ Yorùbá]]
[[Category:Nigerian Muslims]]
[[Ẹ̀ka:Àwọn òṣeré Yorùbá]]
[[Category:Nigerian male film actors]]
[[Ẹ̀ka:Àwọn òṣeré ará Nàìjíríà]]
[[Category:Male actors from Abeokuta]]
[[Category:Male actors in Yoruba cinema]]
[[Category:Yoruba male actors]]
[[Category:21st-century Nigerian male actors]]
[[Category:Olabisi Onabanjo University alumni]]
[[Category:Yoruba filmmakers]]
[[Category:Yoruba-language film directors]]
[[Category:Entertainers from Ogun State]]
[[Category:Nigerian film producers]]
[[Category:Nigerian media personalities]]

Àtúnyẹ̀wò ní 10:05, 24 Oṣù Ọ̀wàrà 2024

Àdàkọ:Unreliable sources

Lateef Adedimeji
Adedimeji at AMAA 2021
Ìbí1 Oṣù Kejì 1984 (1984-02-01) (ọmọ ọdún 40)
Isolo, Lagos State, Nigeria
Iṣẹ́
  • Renowned Actor
  • filmmaker
(Àwọn) ìyàwó
Oyebade Adebimpe (m. 2021)

Adetola Abdullateef Adedimeji Yo-Adetola Abdulateef Adedimeji.ogg Listen (wọ́n bí i ní February 1, 1984) ó jẹ́ ọmọ orílẹ́-èdè Nigerian òṣèré àti Agbéréjáde. [1][2] Ọ̀pọ̀ ènìyàn ni wọ́n mọ̀ ọ́n fún ipa gbòógì rẹ̀ àkọ́kọ́ tí ó kó nínú eré Yéwándé (Yewande Adekoya)'s ní ọdún 2013 èyí tí ó pe àkọlé rẹ̀ ní Kudi Klepto bẹ́ẹ̀ ni ó ti kó ipa takuntakun nínú àwọn eré tí wọ́n lé ní ọgọ́rùn-ún (100) [3] Ó bẹ̀rẹ̀ sí ní kó ipa nínú eré orí ìtàgé àti àgbéléwò láti bí ọdún mẹ́ẹ̀dógún. Òun ni ó jẹ́ aṣojú ìpolówó brand ambassador fún ilé iṣẹ́ Airtel àti Numatville Megacity.[4]

Ìbẹ̀rẹ̀ pẹ̀pẹ̀ ayé rẹ̀

Wọ́n bí Lateef Adedimeji ní ọjọ́ kì-ín-ní, oṣù kejì, ọdún 1984 ni agbegbe kan tí wọ́n ń pè ní Isolo, Lagos State. Ó jẹ́ ọmọ Abeokuta, ní Ìpínlẹ̀ Ògùn Ogun State.[5]

Ètò ẹ̀kọ́ rẹ̀

Lateef bẹ̀rẹ̀ ètò ẹ̀kọ́ rẹ̀ ní Ire Akari Primary School, Isolo, Lagos State, bẹ́ẹ̀ ni ó lọ sí Ilamoye Grammar School Okota ní Ìpínlẹ̀ Èkó Lagos State fún ètò ẹ̀kọ́ girama. [1] Bẹ́ẹ̀ ni ó kẹ́kọ̀ọ́ ní Onikan tí ó wà ní Ìpínlẹ̀ Èkó Lagos State níbi tí ó ti kẹ́kọ̀ọ́ nípa ìṣeré orí ìtàgé. [1] Ẹ̀bùn ìkọ̀wé rẹ̀ àti bí a ṣe ń ṣeré orí ìtàgé gbèrú si lábẹ́ àjọ kan tí kìí ṣe ti ìjọba Non-governmental organization (NGO) èyí tí orúkọ rẹ̀ ń jẹ́ (Community Life Project). [1] Ó kẹ́kọ̀ọ́ gboyè ní ilé ẹ̀kọ́ Olabisi Onabanjo University, níbi tí ó ti gba oyè ìjìnlẹ̀ àkọ́kọ́ [[bachelor's degree] nínú Mass Communication.[6]

Iṣẹ́ rẹ̀

Lateef Adedimeji bẹ̀rẹ̀ sí ní kópa lórí ìtàgé láti ọdún 2007, ó bẹ̀rẹ̀ iṣẹ́ òòjọ́ rẹ̀ pẹ̀lú ijó jíjó, [1] tí ó sì tún lọ ilé ẹ̀kọ́ tí a ti ń kọ́ nípa ijó jíjó. Ó jẹ́ òṣèré Actor tí ó ti kó ipa onírúurú lórí ìtàgé láti ìgbà tí ó ti wà ní ọmọ ọdún mẹ́ẹ̀dógún ṣùgbọ́n tí ó bẹ̀rẹ̀ sí ní ṣe eré ní ọdún 2007 nígbà tí ó dara pọ̀ mọ́ Orisun TV. Ó ṣiṣẹ́ gẹ́gẹ́ bíi atọ́kùn ètò ní ilé iṣẹ́ agbóhùngbójìjí ti Orísun TV, orúkọ ètò tí ó máa ń ṣe nípa à ń ṣe eré orí ìtàgé ni Sábàbí. Ní ìgbà tí ó wà ní ilé ẹ̀kọ́ gírámà, gẹ́gẹ́ bí ẹni tí ó ti ń ṣe eré orí ìtàgé, àwọn àjọ kan tí wọn kì í ṣe ti ìjọba yàn án gẹ́gẹ́ bíi aṣojú àti olúdánilẹ́kọ̀ọ́ lórí àìsàn kògbóògùn HIV/AIDS èyí tí ọ̀pọ̀ ènìyàn máa ń kó láti ara ìbálòpọ̀ akọ sí abo lọ́nà tí kò ní ìdáàbò bò. Iṣẹ́ Lateef Adedimeji ni láti kó ipa nínú eré tí ó máa dá àwọn ènìyàn lẹ́kọ̀ọ́ lórí àwọn ààrùn tí a le kó láti ara ìbálòpọ̀, àwọn ewu tó wà nínú kí á má tọ́jú ààrùn náà àti bí wọ́n ṣe le di ààrùn kògbóògùn, bẹ́ẹ̀ ni ó tún kópa nínú jíjẹ́ kí àwọn ènìyàn ó mọn ẹ̀tọ́ àti ojúṣe wọn lábẹ́ òfin. Lateef jẹ́ ẹnìkan tí ó tètè ṣe àwárí ara rẹ̀ nínú kíkópa nínú eré orí ìtàgé tí ó sì gbé ìgbésẹ̀ láti wọ ẹgbẹ́ àwọn òǹṣèré. Ó ti kó ipa onírúurú bẹ́ẹ̀ ni ó ti bá àwọn òṣèré jàǹkànjàǹkàn ṣe eré àgbéléwò papọ̀ láti ìgbà tí ó ti darapọ̀ mọ́ ẹgbẹ́ àwọn òṣèré tíátà. Ọ̀pọ̀ ni ó mọ̀ ọ́n fún ipa tí ó máa ń kó gẹ́gẹ́ bíi ẹni tí omi ẹkún kò jìnnà sí lójú. Ní ọdún 2016, ó gba àmì ẹ̀yẹ 2016 Best of Nollywood Awards fún òṣèré tí ó léwájú jùlọ nínú eré Yorùbá. [7] In 2015, he was nominated for City People Entertainment Awards for the 2015 Most Promising Actor of the year. Ọ̀pọ̀ àwọn ènìyàn a tilẹ̀ máa ń pè é ní àbúrò òṣèré kùnrin n nì ẹni tí orúkọ rẹ̀ ń jẹ́ Ọ̀dúnladé Adékọ́lá ṣùgbọ́n èyí tí kò rí bẹ̀. Ẹ̀bùn ìkọ̀wé tí ó ní ti mú un bá àjọ àgbáyé UNICEF dá iṣẹ́ papọ̀ rí. [8] He was awarded the face of Nollywood male[9] during the ENigeria Newspaper Night of Honour on 30 October 2021.

Ìgbésí ayé rẹ̀

Ní ọjọ́ kejìdínlógún, 18 December 2021, Adedimeji gbé akẹgbẹ́ rẹ̀ níyàwó, ẹni tí òun náà jẹ́ òṣèré eré orí ìtàgé, Oyebade Adebimpe pẹ̀lú ìgbéyàwó alárinrin. [10][11]

Àwọn eré tí ó ti kó ipa

Àmì ẹ̀yẹ àti ìfidánilọ́lá

Year Award ceremony Prize Result Ref
2014 Odua Movie Awards Best Actor Gbàá [18]
2015 Gbàá
Best of Nollywood Awards Best Actor in a Lead Role (Yoruba) Wọ́n pèé
City People Entertainment Awards Most Promising Actor of the Year (Yoruba) Wọ́n pèé
2016 Best Supporting Actor Of The Year (Yoruba) Gbàá
Best of Nollywood Awards Best Actor in a Lead Role (Yoruba) Wọ́n pèé
2018 Best of Nollywood Awards Best Actor in a Lead Role (Yoruba) Gbàá [19]
City People Movie Awards Best Actor Of The Year (Yoruba) Wọ́n pèé
2019 Best of Nollywood Awards Best Actor in a Lead Role (Yoruba) Wọ́n pèé [20]
Best Supporting Actor (Yoruba) Gbàá
2020 2020 Best of Nollywood Awards Best Actor in a Lead role –Yoruba Wọ́n pèé [21]
2021 Africa Movie Academy Awards Best Actor in a Leading Role Wọ́n pèé [22]
2022 Hollywood and African Prestigious Awards (HAPA Awards) Best Actor in Africa Gbàá [23]

See also

Àwọn Ìtọ́kasí

  1. 1.0 1.1 1.2 1.3 1.4 The360reporters (18 July 2021). "Lateef Adedimeji Net Worth: Lateef Adedimeji Biography, Age, Career And Net Worth.". The360Report (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 20 November 2021. 
  2. "Lateef Adedimeji: The more the fame, the more we need a lot of improvement". The Guardian Nigeria News - Nigeria and World News (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2022-05-21. Retrieved 2022-07-17. 
  3. Mbuthia, Mercy (1 February 2021). "Lateef Adedimeji biography: age, wife, children, net worth, songs". Legit.ng – Nigeria news. (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 20 November 2021. 
  4. "Biography and net worth of Lateef Adedimeji". 
  5. Àṣìṣe ìtọ́kasí: Invalid <ref> tag; no text was provided for refs named theinfopro.com.ng
  6. "7 emerging Yoruba movie stars you need to know". Pulse.ng. 16 April 2019. 
  7. "Lateef Adedimeji Biography". quopedia.blogspot.com. 
  8. "Lateef Adedimeji Biography and Network 2019". theinfopro.com. 
  9. "Premium Times – Nigeria leading newspaper for news, investigations" (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 20 November 2021. 
  10. "See photos from actor Lateef Adedimeji wedding wit colleague Adebimpe Oyebade". 18 December 2021. 
  11. "Lateef Adedimeji clinches international award - P.M. News" (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2022-08-02. 
  12. "Movies Featuring Lateef Adedimeji". ibakatv.com. 
  13. "New Nollywood comedy 'Breaded Life' hits cinemas" (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 16 April 2021. Retrieved 20 April 2021. 
  14. Nwogu, Precious (3 June 2021). "Check out the new teaser for Kayode Kasum & Dare Olaitan's 'Dwindle!'". Pulse Nigeria (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 10 June 2021. 
  15. Nwogu, Precious (14 December 2020). "Tunde Kelani announces production of Ayinla Omowura biopic titled 'Ayinla'". Pulse Nigeria. Retrieved 12 May 2021. 
  16. Nwogu, Precious 'Mamazeus' (2022-04-04). "Biodun Stephen's movie 'Strangers' based on true events set for April release". Pulse Nigeria (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2022-04-19. 
  17. "Ile Alayo: Lateef Adedimeji leaves viewers amused in season 2". Vanguard News. July 17, 2022. Retrieved July 29, 2022. 
  18. "Lateef Adedimeji: Biography, Career, Movies & More". 24 May 2018. 
  19. Augoye, Jayne (10 December 2018). "BON Awards 2018: Tope Oshin, Tana Adelana win big" (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 9 October 2021. 
  20. Bada, Gbenga (15 December 2019). "BON Awards 2019: 'Gold Statue', Gabriel Afolayan win big at 11th edition". Pulse Nigeria (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 10 October 2021. 
  21. "Behold hot steppers and winners at BON awards 2020". Vanguard News (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 12 December 2020. Retrieved 11 October 2021. 
  22. Banjo, Noah (29 October 2021). "FULL LIST: Ayinla, Omo Ghetto: The Saga bag multiple nominations at AMAA 2021". Punch Newspapers (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 30 October 2021. 
  23. Online, Tribune (June 7, 2022). "Nollywood actor Lateef Adedimeji bags international award". Tribune Online. Retrieved August 2, 2022. 

Àdàkọ:Authority control