Tóyìn Abraham: Ìyàtọ̀ láàrin àwọn àtúnyẹ̀wò
#WPWP #WPWPNG |
#WPWP #WPWPNG |
||
Ìlà 1: | Ìlà 1: | ||
{{Infobox person|name=Toyin Abraham|image |
{{Infobox person|name=Toyin Abraham|image=Toyin Abraham at AMVCA 2020.jpg|imagesize=|alt=|caption=Toyin Abraham at AMVCA 2020|birth_name=|birth_date={{Birth date and age|df=yes|1980|09|05}}|birth_place=[[Auchi]], [[Edo State|Edo]], Nigeria|othername=|nationality=Nigerian|citizenship=Nigerian|occupation={{flatlist| |
||
*actress |
*actress |
||
*filmmaker |
*filmmaker |
Àtúnyẹ̀wò ní 07:19, 8 Oṣù Ògún 2020
Toyin Abraham | |
---|---|
Toyin Abraham at AMVCA 2020 | |
Ọjọ́ìbí | 5 Oṣù Kẹ̀sán 1980 Auchi, Edo, Nigeria |
Orílẹ̀-èdè | Nigerian |
Ọmọ orílẹ̀-èdè | Nigerian |
Iṣẹ́ |
|
Ìgbà iṣẹ́ | 2003–present |
Toyin Abraham[1] tàbí Olutoyin Aimakhu; ni wọ́n bí ní (September 5, 1984). Ó jẹ́ is a Nigerian òṣèré orí ìtàgé , olùgbéré-jáde àti adarí eré, ọmọ rílẹ̀-èdè Nàìjíríà.[2][3]
Ìbẹ̀rẹ̀ ìgbésí ayé àti ẹ̀kọ́ rẹ̀
Wọ́n bi ní ìlú Auchi, tí ó jẹẹ́ ìlú kan ní town in ìpínlẹ̀ Ẹdó ní orílẹ̀-èdẹ Nàìjírìà. Àmọ́ ṣá, ó bẹ̀rẹ̀ ayé rẹ̀ ní ìlú Ìbàdàn, tí ó jẹ́ olú ìlú ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́ ní ìwọ̀ Oòrùn ilẹ̀ Nàìjíríà.[4] Ó gba ìwé ẹ̀rí HND (Higher National Diploma) ní ilé-ẹ̀kọ́ gbogbo-nìṣe ìlú Ìbàdàn ìyẹn (Ibadan Polytechnic), lásìkọ́ yí, ó jẹ́ akẹgbẹ́ pẹ̀lú Dibie, C.B.N aka x7,[5] Tóyìn Abraham ti fara hàn nínú ọ̀pọ̀lọpọ̀ eré, tí ó sì tún ṣẹ̀ṣẹ̀ kópa nínú sinimá àgbéléwò aré tí orúkọ̀ rẹ̀ ń jẹ́ Black Val.[6]
Iṣẹ́ rẹ̀
Tóyìn bẹ̀rẹ̀ eré orí ìtàgé rẹ̀ nígbà tí gbajú-gbajà òṣèré orí-ìtàgé tí orúkọ rẹ̀ ń jẹ́ Bukky Wright, wá sí ìlú Ìbàdàn láti yàwòrán eré kan .[7] Ó ti darí, kópa àti gbé eré jáde fúnra rẹ̀, lára rẹ̀ ni Àlání Bàba Làbákẹ́ àti d Èmi ni[8]. Wọ́n yàán gẹ́gẹ́ bí òṣèré amúgbá-lẹ́gbẹ̀ẹ́ obìnrin tó dára jùlọ (Best Supporting Actress) nínú eré orí ìtàgé tí orúkọ rẹ̀ ń jẹ́ "Ẹ̀bi mi ni" nínú àmì ẹ̀yẹ 2013 Best of Nollywood Awards , bákan náà ni wọ́n yan Jọkẹ́ Múyìwá fún Best Lead Actress nínú eré tí àkọ́lé rẹ̀ ń jẹ́ Ayítakẹ̀.[9] Ẹ̀wẹ̀, ọ̀pọ̀ àwọn olóṣèlú ló ti pèé láti bá wọn polongo ètò ìdìbò fún Ààrẹ ilẹ̀ Nàìjíríà tẹ́lẹ̀ tí ó jẹ́ adíje dupò sí orí àpèrè Ààrẹ ìyẹn Goidluck Ebele Jonathan ní ọdún 2015. Tóyìn pàá pàà só wípé òun lè kú torí ẹgbẹ́ òṣèlú Oeopel Democratic Party (PDP) kú[10] tí ó jẹ́ ẹgbẹ́ òṣèlú tí adíje dupò náà ti ń díje. Àmọ́ ṣá, ó padà yí gbólóhùn rẹ̀ padà wípé òun bẹ àwọn olólùfẹ́ òun wípé kí ẹnikẹ́ni ó má ṣe ta ẹ̀jẹ̀ ẹnikẹni sílẹ̀ lásìkò ìdìbò.[11]
Àwọn eré ìtàgé rẹ̀
- Okafor's Law (2016)
- Love is in the Hair (2016)
- Àlàní Bàbá Làbákẹ́ (2013)
- Ẹ̀bi mi ni (2013)
- Alákadá (2013)
- Ṣọlá fẹ́ pa mí
- Ghost and the tout (2018)
Ẹ tún le wo
- List of Nigerian film producers
Àwọn ìtọ́ka sí
- ↑ "Nollywood Star, Aimakhu Now To Be Called Toyin Abraham". Channels Television. https://www.channelstv.com/2016/12/29/nollywood-star-aimakhu-now-to-be-called-toyin-abraham/. Retrieved 30 December 2016.
- ↑ Empty citation (help)
- ↑ Empty citation (help)
- ↑ Empty citation (help)
- ↑ Empty citation (help)
- ↑ Empty citation (help)
- ↑ Empty citation (help)
- ↑ Empty citation (help)
- ↑ Empty citation (help)
- ↑ "I am ready to die for PDP-Toyin Aimakhu". Gistmaster. http://niyitabiti.net/2015/03/i-am-ready-to-die-for-pdp-toyin-aimakhu/. Retrieved 2018-01-03.
- ↑ Empty citation (help)
Àwọn ìjásóde
- Toyin Abraham on IMDb