Louise Barnes
Ìrísí
Louise Barnes | |
---|---|
Ọjọ́ìbí | Louise Barnes 26 Oṣù Kẹrin 1974 South Africa |
Iṣẹ́ | Actress, voice artist |
Ìgbà iṣẹ́ | 2004–present |
Louis Barnes (bíi ni ọjọ́ kerìndínlọ́gbọ̀n oṣù kẹrin, ọdún 1974)[1] jẹ́ òṣèré ni orílẹ̀ èdè South Áfríkà. Ó di gbajúmọ̀ fún ipá tí ó kó nínú eré Surviving Evil ni ọdún 2009. Ó kọ ipa Miranda Barlow nínú eré Black Sails ni ọdún 2014.
Ayé àti ẹ̀kọ́ rẹ̀
Wọ́n bí Barnes sì ìlú KwasZulu-Natal, ó sì gboyè nínú ìmò Dramatic Art láti ilé ẹ̀kọ́ gíga tí University of Witwatersrand.
Iṣẹ́
Barnes tí kópa nínú orísìírísìí eré bíi Egoli, 7de Laan, Binnelanders, Scandal!, Sorted, Suburban Bliss ati S.O.S.
Àṣàyàn àwọn eré rẹ̀
Fiimu
Year | Film | Role | Notes |
---|---|---|---|
1993 | Where Angels Trend | - | |
2002 | Borderline | Karen Kendler | |
2003 | Hoodlun & Son | Celia | |
2004 | Critical Assignment | Laura | |
2009 | Surviving Evil | Rachel Rice |
Telefiisionu
Year | Film | Role | Notes |
---|---|---|---|
1996 | Suburban Bliss | ||
1997-2000 | Egoli | Adele de Bruyn de Koning | |
2006-2007 | Jozi-H | Jocelyn Del Rossi | |
2011 | The Sinking of the Laconia | Mary Bates | |
2009-2013 | Scandal! | Donna Hardy | SAFTA Winner—Best Actress in a TV Soap[2] |
2014-2016 | Black Sails[3][4] | Miranda Barlow | |
2017 | Outsiders | Moregon | |
2019 | NCIS | Sarah/Sahar |
Àwọn Ìtọ́kasí
- ↑ "Donna Hardy". e.tv. 1974-04-26. Archived from the original on 19 June 2013. Retrieved 13 May 2013. Unknown parameter
|url-status=
ignored (help) - ↑ http://www.etv.co.za/news/2013/04/15/louise-barnes-life-after-scandal
- ↑ "Black Sails" (in en). EW.com. Archived from the original on 2015-01-06. https://web.archive.org/web/20150106075136/http://www.ew.com/ew/article/0,,20779458,00.html.
- ↑ KpopStarz (2014-08-14). "'Black Sails' Season 2 Trailer And Release Date: Starz Bought Season 2 Of 'Treasure Island' Prequel Before Season 1 Aired [VIDEO"]. KpopStarz. http://www.kpopstarz.com/articles/104120/20140814/black-sails-season-2.htm.