Jump to content

Yunifásítì Abubakar Tafawa Balewa

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Yunifásítì Abubakar Tafawa Balewa
Abubakar Tafawa Balewa University
The crest of ATBU
Motto"Doctrina matter artium"
(Education is the mother of the practical arts)
Established1980
TypePublic
PresidentProfessor Garba A. Babaji
Admin. staff?
Undergraduates? full-time, ? part-time (2005)
Postgraduates? full-time, ? part-time (2005)
LocationBauchi, Northern Nigeria, Nigeria
CampusUrban
Mascot?
AffiliationsAssociation of African Universities
Websitehttp://www.atbunet.org
Crest image © Abubakar Tafawa Balewa University


Ifásitì Abubakar Tafawa Balewa tí a mọ̀ sí (ATBU) jẹ́ ilé-ẹ̀kọ́ gbogbonìṣe àgbà tí ó wà ní ìlú Bauchi, ní orílẹ̀-èdè Nàìjíríà. Wọ́n sọ ilé-ẹ̀kọ́ náà ní orúkọ rẹ̀ tí ó ń jẹ́ ní orúkọ Alákòóso àgbà àkọ́kọ́ fún orílẹ̀-èdè Nàìjíríà tí wọ́n ń pè ní Sir Abubakar Tafawa Balewa. Àkọmànà ilé-ẹ̀kọ́ náà ni:"Doctrina Mater Artium", tí ó túmọ̀ sí "Ẹ̀kọ́ ni atọ́nà fún ìṣe".[1]

Wọ́n dá ilé-ẹ̀kọ́ náà kalẹ̀ ní ọdún 1980 gẹ́gẹ́ bi ilé-ẹ̀kọ́ gbogonìṣe àgbà ní ìlú Bauchi. Wọ́n sì gba àwọn akẹ́kọ̀ọ́ àkọ́kọ́ wọlé ní inú oṣù kẹwàá ọdún 1981 fún ìkékọ̀ọ́-gboyè ìpele ì̀bẹ̀rẹ̀ dìgírì kínní, nígbà tí ìkẹ́kọ̀ọ́ dìgírì ti ìmọ̀ ẹ̀kọ́ ìkọ́ni sáyénsì bẹ̀rẹ̀ ní inú oṣù kẹwàá ọdún 1982. Ní ọjọ́ kínní oṣù kẹwàá ọdún 1984, wọ́n da ilé-ẹ̀kọ́ fá́sìtì̀ Abubakar Tafawa Balewa pọ̀ mọ́ ilé-ẹ̀kọ́ Ahmadu Bello University gẹ́gẹ́ bí ilé-ẹ̀kọ́ kan ṣoṣo tí wọ́n sì yí orúkọ àwọn méjèèjì padà sí 'Abubakar Tafawa Balewa College' gbọ̀gàn ìkẹ́kọ̀ọ́ ti Ahmadu Bello University ní Bauchi. Ilé-ẹ̀kọ́ Ifásitì Abubakar Tafawa Balewa gba òmìnira padà gẹ́gẹ́ bí ilé-ẹ̀kọ́ nígbà tí wọ́n tún pín wọn níyà, tí wón si sọ̀ ọ́ ní Ifásitì Abubakar Tafawa Balewa ti ìlú Bauchi

Àwọn ìtọ́kasí

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]
  1. Fapohunda, Olusegun (2021-10-09). "List Of ATBU Courses & Programmes Offered". MySchoolGist (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2023-01-10.