Jump to content

Íṣẹ́ológun

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
(Àtúnjúwe láti Military)

Íṣẹ́ológun ni agbajo ti o ni ase lati lo ipa, nigba miran pipo pelu ohun ijagun, lati da abo bo orile-ede won lati koju ewu gidi tabi to le wa. Ologun ni a n pe gbogbo ohun to je mo ti Ise-ologun. Awon ise-ologun nigba miran n sise bi awujo ninu awujo nipa nini awujo ologun ti won nikan, isuna, eko, iwosan ati awon apa miran awujo aralu.

Agbase ise jagunjagun gege bi apa adipo ologun kan dagba ju itan abalaye fun ra re lo. Awon aworan ti ko se gbagbe lati aye ijoun se afihan agbara ati itù awon olori ologun won. Ija Kadesh ni odun 1274 kJ ni ikan ninu igba pataki ite Farao Ramesses Keji ti won si sajoyo re gidi.[1] Egberun odun leyin eyi alayeluwa apapo Ṣáínà Qin Shi Huang, mura kitankitan lati te awon olorun lorun pelu agbara ologun to je pe won sin pelu adigun amo.[1]





  1. 1.0 1.1 Bas-relief of Ramesses II at Kadesh Àṣìṣe ìtọ́kasí: Invalid <ref> tag; name "ReferenceA" defined multiple times with different content