Omawumi
Omawumi | |
---|---|
Omawumi Megbele during an interview in 2016 | |
Background information | |
Orúkọ àbísọ | Omawumi Megbele |
Wọ́n tún mọ̀ọ́ bíi | Omawumi |
Ọjọ́ìbí | 13 Oṣù Kẹrin 1982 Delta State, Nigeria[1] |
Ìbẹ̀rẹ̀ | Warri, Delta State |
Irú orin | Soul,[2] R&B,[3] pop,[4] afro-pop[2] |
Occupation(s) | Singer, songwriter, actress |
Years active | 2007–present |
Associated acts | 2Face Idibia, Timaya, Flavour N'abania, wizkid, Cobhams Asuquo, Lynxxx |
Omawumi Megbele (tí a bí ní ọjọ́ kẹtàlá, oṣù kẹrin ọdún 1982), tí a mọ̀ sí Omawumi jẹ́ olórin orílẹ̀-èdè Nàìjíríà, akọrin sílẹ̀ àti òṣèré tí ẹ̀yà Itsekiri.[5] Ó jẹ́ brand ambassador fún Globacom,[6], Konga.com, àti Malta Guinness. Ó dara pọ̀ mọ́ kàm̀páìnì kan tí ń jẹ́ "Rise with the Energy of Africa".[7] Ní ọdún 2007 tí ó kópa nínú West African Idols tí ó sì yege pẹ̀lú ipò kìíní ní àwọn èèyàn bẹ̀rẹ̀ sí ní mọ̀ ọ́.[8] Album rẹ̀ The Lasso of Truth tí ó ṣìkejì ṣe já sí àṣeyọrí ńlá ní orílẹ̀-èdè Nàìjíríà.[9]
Ìgbésí ayé rẹ̀
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Ìbẹ̀rẹ̀ ayé àti ètò-èkó rẹ̀
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]A bí Omawumi sínú ìdílé Chief Dr. Frank àti Mrs. Aya Megbele ní ọjọ́ kẹtàlá, oṣù kẹrin ọdún 1982. Ó lọ sí Nana Primary School nígbà tí ó wà ní kékeré, kí ó tó wá lọ sí College of Education Demonstration Secondary School. Ó lọ sí Ambrose Alli University ó sì jáde pẹ̀lú degree nínú Law. Lẹ́yìn tí ó jáde ní ilé-ẹ̀kọ́ gíga ní ọdún 2005, ó kó lọ sí ìlú Port Harcourt ní ìpínlẹ̀ Rivers State, níbi tí ó ti ṣiṣẹ́ pẹ̀lú ilé-iṣẹ́ amòfin "O.S Megbele & Associates" ti ẹbí rẹ̀. Ó tún lọ sí Alliance Francaise níbi tí ó ti gboyè nínú French. Ní ọjọ́ kẹtàlá, oṣù kìíní ọdún 2018, Toyin Yusuf gbé e níyáwòó.
Ààtò àwọn àmì ẹ̀yẹ tí ó gbà
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Year | Event | Prize | Recipient | Result | Ref |
---|---|---|---|---|---|
2009 | The Headies 2009 | Best Vocal Performance (Female) | "In the Music" | Gbàá | |
2014 | ELOY Awards | Best Female Artist | N/A | Wọ́n pèé | [10] |
2016 | The Headies 2016 | Best Vocal Performance (Female) | "Play Na Play" (featuring Angélique Kidjo) | Wọ́n pèé | [11][12] |
2018 | The Headies 2018 | Best Recording of the Year | "Butterflies" | Wọ́n pèé | [13] |
Best Vocal Performance (Female) | Gbàá |
Àwọn Ìtọ́kasí
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ "Omawumi @Omawumi – Artist Profile". Africax5.tv. Archived from the original on 22 February 2014. Retrieved 16 February 2014.
- ↑ 2.0 2.1 "Bands We Like: Nigerian Singer Omawumi’s Powerful Voice". MTV Iggy. 26 January 2011. Retrieved 16 February 2014.
- ↑ "Omawumi, Ice Prince debut in Yvonne Nelson's new movie". Vanguard News. 1 February 2013. Retrieved 16 February 2014.
- ↑ "Omawumi gives birth to baby girl in US". Vanguard News. 20 June 2011. Retrieved 16 February 2014.
- ↑ "I never knew I would become a musician – Omawumi". Nigerian Tribune. 28 December 2013. http://www.tribune.com.ng/news2013/index.php/en/component/k2/item/29511-i-never-knew-i-would-become-a-musician-%E2%80%93-omawumi.html. Retrieved 4 January 2014.
- ↑ "Glo Picks Omawumi, Others As New Ambassadors". PM News. 10 May 2013. http://www.pmnewsnigeria.com/2013/05/10/glo-picks-omawumi-others-as-new-ambassadors/. Retrieved 10 May 2013.
- ↑ "my first job was the team song I did for Malta Guinness with Cohbams Asuquo". vanguard. 29 October 2011. http://www.vanguardngr.com/2011/10/im-happy-im-in-love-omawunmi/. Retrieved 29 October 2011.
- ↑ Yemisi, Adeniran (22 June 2013). "Omawumi Megbele: Red, hot and rising". National Mirror. Archived from the original on 4 March 2016. https://web.archive.org/web/20160304234349/http://nationalmirroronline.net/new/omawumi-megbele-red-hot-and-rising/. Retrieved 4 January 2014.
- ↑ Olatuja, Adebimpe (27 December 2013). "Music: Best of entertainment in 2013". National Mirror. Archived from the original on 24 October 2014. https://web.archive.org/web/20141024103511/http://nationalmirroronline.net/new/music-best-of-entertainment-in-2013/. Retrieved 4 January 2014.
- ↑ "Seyi Shay, Toke Makinwa, Mo'Cheddah, DJ Cuppy, Others Nominated". Pulse Nigeria. Chinedu Adiele. Archived from the original on 3 July 2017. Retrieved 20 October 2014.
- ↑ Akan, Joey. "Headies 2016, Full Winners List". Archived from the original on 15 May 2018. Retrieved 15 May 2018.
- ↑ "The Headies Awards 2016: Complete list of Nominees - INFORMATION NIGERIA". INFORMATION NIGERIA. 9 November 2016. Retrieved 15 May 2018.
- ↑ "Headies releases nominees for 2018 awards [FULL LIST] - Daily Post Nigeria". Daily Post Nigeria. 13 April 2018. Retrieved 14 April 2018.