Jump to content

Roza Otunbayeva

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Roza Otunbayeva
Роза Отунбаева
President of Kyrgyzstan
Lọ́wọ́lọ́wọ́
Ó gun orí àga
3 July 2010
AsíwájúKurmanbek Bakiyev
Prime Minister of Kyrgyzstan
Acting
In office
7 April 2010 – 19 May 2010
AsíwájúDaniar Usenov
Arọ́pòVacant
Minister of Foreign Affairs
In office
1992–1992
ÀàrẹAskar Akayev
Alákóso ÀgbàTursunbek Chyngyshev
Àwọn àlàyé onítòhún
Ọjọ́ìbí23 Oṣù Kẹjọ 1950 (1950-08-23) (ọmọ ọdún 74)
Osh, Soviet Union (now Kyrgyzstan)
Ẹgbẹ́ olóṣèlúSocial Democratic Party
Alma materLomonosov Moscow State University

Roza Isakovna Otunbayeva (Àdàkọ:Lang-ky, Rọ́síà: Роза Исаковна Отунбаева; ọjọ́ ibi August 23, 1950) ni Aare orílẹ̀èdè Kyrgyzstan. Wọ́n búra fún un ní July 3, 2010, lẹ́yìn tó ti dípò bí i olórí fún ìgbà díẹ̀ lẹ́yìn ijidide April 2010 tó fa lílé kúrò Ààrẹ Kurmanbek Bakiyev lórí ipò. Otunbayeva jẹ Alákóso ọ̀rọ̀ òkèrè tẹ́lẹ̀ àti olórí ìpàdé ilé aṣòfin fún Ẹgbẹ́ Tòṣèlú aráàlú Àwùjọ ilẹ̀ Kyrgyzstan. Roza Isakovna Otunbayeva jẹ́ ẹni pàtàkì nínú ìṣèlú orílẹ̀-èdè Kyrgyzstan, tí a mọ̀ fún ipa pàtàkì rẹ̀ nínú mímú ìlú náà ni ṣẹ nípasẹ̀ àkókò ìsọdọ̀tun ìṣèlú. Otunbayeva ni obìnrin àkọ́kọ́ tí yíò jẹ Ààrẹ orílẹ̀-èdè ọmọ ẹgbẹ́ CIS/SCO. Bákan náà, ó ti jẹ́ Ajàfẹ́tọ̀ó àwọn obìnrin, tí ó sì ti kó àwọn ipa takuntakun nínú ètò láti gbé ẹ̀kọ́, àwùjọ ìlú, àti ìjàfẹ́tọ̀ọ́ ọmọnìyàn síwájú si ní Ìlà Oòrùn Àárín ti Asia.