Orin Owuro
Orin Owuro
Orin Owuro
1. C.MAgo Re wonni ti li
ewa to,Oluwa awon omo
OgunOD. 84:11 fp
Olus‘agutan eni Re
Fi ara Re han wa,
‗Wo fun wa n‘ile
aduraM‘okan wa
gbadura
2. mf Fi ami ife Re han w
aSo ireti wa ji
Se‘ri‘bukun Re s‘ori
waK‘awa le ma yin O
3 mf
K‘ife ati alafiaK‘o ma
gbe ile yi!
F‘irora f‘okan iponju
M‘okan ailera le
4 mf
F‘eti igbo, aya ‗gbase,
Oju ‗riran fun wa;
Tan imole Re lat‘oke
K‘a dagba l‘or‘ofe
5 mf
K‘a fi gbagbo gbo oro Re
K‘a f‘igbagbo
bebeAti niwaju Oluwa
K‘a se aroye wa.
Amin
5 L.MNigbawo ni ikwo o
to mi wa?OD 101:21 mf
Wa s‘odo mi, Oluwa mi,
Ni kutukutu owuro,
Mu k‘ero rere so jad
e,
Lat‘inu mi s‘oke orun
2
Wa s‘odo mi, Oluwa mi,
Ni wakati osan gangan;
Ki ‗yonu ma ba se mi
mo,
K‘o si so osan mi d‘oru.
3 mp
Wa s‘odo mi, Oluwa mi,
Nigbati ale ba nle lo,Bi
okan mi ba nsako lo,
Mu pada, f‘oju ‗re wo
mi.
4
Wa s‘od
o mi, Oluwa mi,
L‘oru, nigbat‘oru ko si,
P Je ki okan aisimi mi,Si
mi le okan aya Re.5 mp
Wa s‘oso mi, Oluwa mi,
Ni gbogbo ojo aye
mi,p Nigbati emi mi ba pi
nf
Ki nle n‘ibugbe l‘odo Re.
AMIN
6 7.7.7.DSugbon orun
ododo yio la fun eniyan ti
O beru oruko Mi. Mal
4:21 f
Krist‘t‘ogo Re ka aye,
Krist, Imole Otito;Orun
ododo dide,
K‘o si bori okunkun
‗mole ooro, sunmo mi,
‗Rawo oro yo n‘nu mi
2 mp Ooro to de laisi Re,
Ookun on ‗banuje ni,
Ile to
mo ko l‘ayo,
Bi nko r‘oye anu Re,
B‘Iwo ko fi ‗mole Re
Kan oju on okan
mi3 mf Nje be okan mi yi
wo,Le okunkun ese lo,
F‘imole orun kun mi,
Si tu aigbagbo mi ka
Maa f‘ara Re han mi si
Titi di ojo pipeAMIN
9 7.7.7.7.3Ohun mi ni
Iwo o gbo li owuro,
Oluwa. OD
5:31 f Jesu, Orun ododo,I
wo imole ife
‗Gbati ‗mole Owuro,Ba
nt‘ila orun tan wa,Tan
‗mole ododo Re
Yi wa
ka2 mp Gege be iri ti nse,
S‘ori eweko
gbogbo,K‘Emi ore
-ofe Re
S‘o okan wa di otun,
Ro ojo ibukun
Rep Sori Wa3 mf
B‘imole orun ti
nran,K‘imole ife TireSi
ma gbona l‘okan wa,K‘o
si mu wa l‘ara yaK‘a le
ma f‘ayo sin O.L‘aye wa.
4 Amona ireti wa,Ma fi wa
sile titi,
Fi wa s‘abe iso Re
Titi opin emi wa,Sin wa
la ajo wa ja
S‘ile wa
5
Ma to wa l‘ona toro
L‘ojo aye wa gbogbo
Sin wa la ekun re ja,
Mu wa de ‗le ayo na
cr
K‘a le ba won mimo gba
p Isimi.AMIN
10 6.6.6.6Gbo ekun mi,
Olorun; fiyesi adura
mi.OD 61:11 mp
Baba mi, gbo
t‘emi, ‗Wo ni alabo mi,
Ma sun mo mi titi,Oninure
Julo2 Kristi Oluwa mi,
Iye at‘ogo mi,Ki ‗gba
naa yara de,
Ti un o de odo
Re.3 p Olutunnu julo,
‗Wo ti ngbe inu
mi, ‗Wo t‘O mo aini
mi,Fa mi, k‘O si gba mi
4 mf Mimo, Mimo, Mimo,
Ma fi mi sile
lae,P Se mi ni bugbe Re,T
ire nikan laelae.AMIN
12 9.6.9.6Abrahamu si
sunmo odo Oluwa. Gen.
18:231
Je ki nsun mo
O l‘ojojumo
Jesu Olugbala
Je ki ngb‘ara le O si,
Jesu
Ni Gbogbo on
li.2 Je ki n fe Ewa Re han,
Jesu,Bi
orun lo‘roke
Je ki ete mi so adun
Re,Pelu ayo
toto,3 Je ki ndabi orisun o
mi,Jesu OlugbalaMa lo mi
l0jojumo, Jesu,Fun ogo
Re nikan4
Lokan ati l‘ero mi,
Jesu,J‘oba patapata
Je ki njeni oloto, Jesu,
Si O l‘ohun gbogbo.
5
Monk‘ebi at‘ongbe Re,
Jesu,Ebi at‘okan wa;
Mo nsaferi ‗le mi ni
Sion;
Nibit‘Olorun wa.
AMIN
13 8.7.11.8.7.11 & RefOl
orun si wipe, Ki imole ki o
wa; imole si wa. Gen.
1:31 mf
‗Mole wa
l‘afonifoji ‗Mole wa l‘ori
oke
Jesu l‘O mu wa s‘aye
Okukun yi,
‗Mole wa l‘ara itanna
To ndagba l‘eba
odo,Imole wa ni ‗bikibi
ti mo nlo;
F
‗Mole, Mole t‘ife Re
orun, ‗Mole, mole,
itansan orun ‗Mole,
mole, li aye wa
yi, ‗Mole, mole, l‘ona
ani
Gbogbo2 mf Imole wa lori
pada
Ati l‘ori koriko
Nibiti awon eye nkorin
iyin;Imole wa lori oke,
‗Mole wa ni petele
Je ki gbogbo eda jumo
korin
‗yin
3 f
B‘aye tile kun fun
‗moleTo si ntan
l‘ojojumo,Okan pupo wa
n‘nu okunkun
Sibe,Ti ko g
b‘oruko Jesu ri,Tabi ife
‗yanu Re,
Je ki a fi oro Re ran won
L‘owo
AMIN
14 C.M
Emi dubule, mo si sun‘
mo si ji;Nitori ti Oluwa ti
mi l‘ehin. OD 3:5
1 mf Ninu gbogbo ewu or
u,
Oluwa l‘o so mi;Awa si
tun ri ‗mole yi
A tun te ekun ba.2
Oluwa, pa wa mo l‘oni,
Fi apa Re so wa;
Kiki awon ti‘wo
pamo,L‘o nyo ninu ewu.
3
K‘oro wa, ati iwa
wa,Wipe, tire l‘awa;
Tobe t‘imole otito
Le tan l‘oju aye.
4 mp
Ma je k‘a pada lodo Re,
Olugbala owon;Ti
ti ao f‘oju wa ri
Oju Re li opin.AMIN
You're Reading a Preview
Upload your documents to download.
Upload to Download
OR
16 L.MEmi o ma fi otito re
han lati irandiran. OD
89:11 f
Baba, a sope ‗toju
Re,T‘o f‘alafia kun ‗le
wa;
Odo Re ni won ti san wa
Owo Re l‘o si ngbe won
ro
2 mf
Olorun, t‘o ye k‘a ma
yin,L‘a nkepe ninu ile
wa;
Oluwa orun, ti ko koLati
ma gbe ile aye.3
Jek‘olukuluku ‗dile
Ma kepe O tosan-toru;
K‘a ko omo at‘om‘odo
L‘ofun at‘ore
-ofe Re.4 f
Beni k‘iran ti mbo ma so
T‘ola ooko Re t‘o
logo,Titi gbogbo wa y‘o
fi lo
Dapo mo idile t‘orun
AMIN
You're Reading a Preview
Upload your documents to download.
Upload to Download
OR
17 C.MOna mi iba je la
sile lati ma pa olana Re
Mo! OD119:51 mf
Oluwa, emi y‘o korinAnu
at‘idajo;Nigbawo n‘Iwo
y‘o fun miN‘imole on iye
2
mo nfe lati t‘ona pipe,
Ki nni okan pipe,Ona,
okan ati ile,Nibiti Iwo
mbe,3 Mo nfe ki awon olo
toJe oluranwo mi;
Ki nfi won s‘ore
-imule
A t‘omo
-odo
mi.4 cr Ki yo si eke at-
etanNinu ibugbe mi;Mp
Oluwa, Jek‘Ibugbe mi
Ye fun O lati gbe!AMIN
You're Reading a Preview
Upload your documents to download.
Upload to Download
OR