Pamphlet 2023
Pamphlet 2023
Pamphlet 2023
Order of programme
Building Materials needed:
Programme Moderator - Pro. Oyedemi Raphael
OLUKORE NAA DETAN Solo: O npada bo, O fere de o, Jesu npada bo,
Chrs: Ile aye mo wa gb'eso/2x, ile aye gb'ege o, onidajo ododo.
ayanfe e mura laiweyin olukore fere de/2x All: O npada bo, O fere de o, Jesu npada bo, onidajo
ododo.
1. Opin aye o ma nkankun eni ba gbon o ko
fura, olukore o ma nbo wa eje ka mura sile HAPPY HOME
fun. Chrs:- Give me happy home Lord, grant me happy
Chrs: Ile aye mo wa gb'eso/2x, ....... Int home father, home where Jesus is reigning, give me
happy home Lord.
2. Emi nbowa, mo nbo Kankan, lati san fun Fun mi nile alayo Oluwa, mo fe ile alayo Baba,
olukaluku o gege bo ti se ninu ara, eniyan e ile ti Jesu ti njoba, fun mi nile alayo. Int
mura lai w'eyin olukore fere de.
Chrs: Ile aye mo wa gb'eso/2x, ........ Int 1. Ile alapeere rere, ile ta fi ngbadura fun ile, ile ti
awon obi ti mo Olorun, t'awon omo je alawo
3. Bi o ba lowo rora se, bi oba kole ma fi ko'se rere. Chrs:-……… Int
gberaga, rin bo tito niwaju Olorun, awon eni
ana da o, se bi gbogbo won lo ti ku, ayanfe e 2. Ki oko gbegba, ki iyawo gbe awo, apeere ile alayo
mura lai w'eyin olukore fere de. ni yen, ile ti Jesu njoba, fun mi nile alayo. Chrs:-
Chrs: Ile aye mo wa gb'eso/2x, ........ Int ….. Int.
4. Eyin ayanfe e teti gbo, ile aye ki s'awailo, 3. Ile ti ko si ibanuje, ile to kun fun alaafia, ile ti pepe
awon akoni won subu, alagbara won pa ipo adura r'aaye, mo fe iru ile yii. Chrs:-…….. Int
da ta lole duro loju ogun, ayanfe e mura lai
w'eyin idajo o fere de. 4. Igbati igbamu ko si ninu ile ti Jesu Oluwa ti njoba,
Chrs: Ile aye mo wa gb'eso/2x, ...... Int ile ti Jesu ti njoba, ile to kun fun ayo. Chrs:-… Int
2 15
2. Nigbati won mu Samsoni tan, e pe bawo ni won ti 5. Iwe ifihan ori kejilelogun ese ikokanla, olotito ko
se, awon ota yo oju re mejeeji, won wa nse e ma se lo, elegbin ko tesiwaju, opuro ole mase
l'egba, won wa okun nla rabata, won fi de Samsoni jafara, onidajo aye nbo, ayanfe o je ronu re, ile
mo igi, baba ta lo tobe lati dan'ru re wo, bi ko ba se aye mo wa gbeso olukore fere de.
to ri t'ese, ese ma n d'oro o, iku ni ere re. Chrs: Ile aye mo wa gb'eso/2x, ile aye gb'ege o,
Chrs:-…….. Int ayanfe e mura (laiweyin/3ce) olukore fere de.
12 5
2. Ba wo l'ogun se le to lajule orun, angeli esu ati 4. Eto mi gbogbo t'esu ti gba mo mi lowo, l'oruko Jesu
t'Olorun lo jo wa ya ija, ninu awon angeli to wa ni mo pada gba eto mi, airina, airilo ko fi mi sile,
lajule orun, ta ba pin won s'ogota o, tesu loko aseiri, asedanu o ya maa lo, emi eni iwaju ti mo pada
ogun kan. di t'eyin, l'oruko Jesu Oluwa ki n deni iwaju pada.
Ka di'gun gba'joba, a se ko ti e sese de, a se Chrs:-…..... Int
latode orun ni digun gba'joba ti bere/2x, omo
ogun esu a ni bi won se po to, awon ogun Olorun, 5. Arakunrin arabinrin ma wule ronu mo, ironu lasan ko
awon ni won bori ogun esu, pelu oruko aseda la fi le gb'eto re fun o, gbogbo agbara l'aye l'orun lo wa
le satani ju sinu aye, lati igba naa lo laye tiwa ninu lodo Jesu, iwo so fun Jesu Oluwa, ko lo gb;eto re wa
inira/2x, satani lo laye yio, alade aye yi lo nje. fun o, ti o ba le gba'dura l'oruko Oluwa, ire re ti o ti
Chrs:-….. nu o gbogbo yi o pada wa to o lowo, mo ba o s'amin,
l'oruko Oluwa, beeni a se.
3. Ninu iwe ifihan, ori kejila ese ikewa logun orun ti
nki ra won, pe nigba yi ni igbala nla wole de, ati OLOPA OTA
agbara ati ijoba Olorun, ati ola Jesu Kristi Chrs:- Ese l'olopa ota o, eyin eniyan e gbo, ese l'olopa
Olugbala, a til e olufisun wa sinu aye/2x ninu ese ota o, to nko ni s'iya je, to ba mu ni a na niyan ni
kejila l'Olorun ti soro, O ni e maa yo eyin orun, kondo, to ba mu ni tan a ti niyan sinu ogun, ebe ni mo
ati eyin to ngbe inu orun, o ya e maa yo, lawon be o Oluwa, mase je ki o ri mi mu./2ce
orun ba m'orin senu e gbo bi won se ko… 1. Ti a ba ranti Samsoni, alagbara baba, o lagbara ko
Ha! asegun re/2x, nipa oro eri enu wa, ati seni to le mu u, to ba d'oro pe ka mu ni, awon ota
nipa eje ti Jesu Kristi, satani ti m'ofo lailai, gbiyanju titi pabo ni gbogbo re ja si, itakun yowu to
lowo re lowa baba lowo re lowa, gbogbo ni k'erin ma w'odo o, ohun at'erin ni yo jo lo, sugbon
agbara/2x Jesu lowo re lowa/2x bo se lagbara ohun to, ese ni won fi mu u, nigba to ti
si ese gbe lati fe obinrin, nipase ajeji obinrin ni
Samsoni so agbara nu, ese l'olopa ota o, ko ni ri wa
mu. Chrs:-…….. Int
4 13
2. Oruko Jesu yii naa lo tun se iyanu, l'enu ona EYIN ONIGBAGBO IJO IGBALA
tempili daradara, ninu aye okunrin aro to ntoro 1. Eyin onigbagbo ijo igbala, gbo oro ti n dun leti yin, ti
owo, o gboju wo'ke o ri Johannu pelu Peteru, o ti nkepe kankun aaye si nbe bo ti le je pe elese l'awa,
ro o l'okan ara re p'olowo ni won, o ko ju si won pe 'gbagbogbo l'oniwaasu nso fun wa, pe mura mase so
e bun mi tori Olorun, Peteru lo soro, e gbo bo ti se emi re nu, tori Oluwa ti o fifun o, O nreti ere kan lori
wi, fadaka pelu wura awa ko ni, sugbon ohun ti a re.Chrs: Yo ti dun mi to, a dun mi pupo, gbati nba
ni la bun o, l'oruko Jesu ti Nazareti, dide ki o maa d'odo Jesu ti emi ko ri o . int
rin, oruko Jesu yii l'agbara oruko nla. 2. Iwe oniwaasu ori kejlla, ese ikini de ekeje, lo nba wa
Chrs:-…….. Int soro onigbagbo aye, ti won ko nani oro igbala, eyin
3. Nigbati paul lo waasu ni ile Troasi, o nba won soro ara e ba tun ranti pe, o ye ka ranti ara iwaju, nigbati
Olorun nibi iso oru, lori oke alaja meta ni won gbe Israeli k'Olorun sile, won d'eni igbagbe ni babeli.
ti duro, odomokunrin kan joko nibe loju window, Chrs: Yo ti dun mi to, ............ int
loju window lo ti sun lo lo ba fi re bo, gbigbe ti won
lo gbe nile oku ni won baa, o je ohun ibanuje fun 3. Opo onigbagbo lo gba Jesu, ti afe aye gbe san lo,
won, won fe maa sunkun, ni Paul bad a won l'ohun won ti gbagbe oloro ijosi, t'oto isura re jo s'aye,
o ni e ma sunkun, ni Paul ba gbadura fun un lo ba fi nigba t'elemi bere emi re, lowo asiwere oloro naa,
ji, oruko Jesu yii l'agbara e wo iyanu. ekun oro ati ipayin keke, l'oloro jere leyin aye re.
Chrs:-……… Int. Chrs: Yo ti dun mi to, ............ int
Solo: Yo seese, kini isoro re, so fun Jesu, a ba o se 4. B'odun ti n de l'ojo wa nsun mole, onigbagbo
All: Yo seese, kini isoro re, so fun Jesu, a ba o se kiyesara, k'adupe lowo metalokan to da emi wa si
Solo: Arakunrin All: Yo seese........ d'ojo oni, a tun nbe o Olorun alanu, ko tubo fun wa
Solo: Arabinrin All: Yo seese........ ni emi gigun, ki opo odun s'oju emi wa ki ari eyi to
Solo: Eyin Baba All: Yo seese........ nbo l'alafia. Chrs: Yo ti dun mi to, .........int
Solo: Eyin Mama All: Yo seese........ All: mapada, ma y'owo re loro mi, ma pada leyin mi oba
Solo: Eyin Odo All: Yo seese........ lailai./2x
6 11
OKO PON FUN IKORE SA ASALA
1. Oko pon fun ikore alagbase ko to o, mo gbo ti Jesu Chrs:- Olorun be sodomu wo, Olorun be Gomorrah
npe mi lohun rara pe, tani emi yo ran lo. wo, awon ti won sa asala, won d'eni igbala,
Chrs:- Tani o/6x, yo lo o, tani o si ti mura tan lati je sa asala ki o ma s'egbe/2x. Int.
ipe Jesu npe, tani emi yo ran lo. Int 1. Loti sa asala, o yo ninu ewu iparun, bi iwo ba sa
asala wa d'eni igbala, tete jawo ninu ese ki o ma
2. Lojojumo ni awon elese nsegbe o, lojojumo ni s'egbe. Chr:-… Int
alaigbagbo n segbe o, lojojumo ni awon eletan n
segbe o, mo gbo ti jesu npe mi lohun rara pe, tani 2. Dafidi sa asala, o yo ninu ewo oba saulu, sa asala
emi yo ran lo. ninu gbogbo ohun idibaje, ohun o ba se laye la o
Chrs:- Tani o/6x, yo lo o, tani o si .............Int fid a o lejo, tete sa asala oni lojo igbala, gba emi
re la, mase so igbala yi nu. Chrs:-..... Int
3. O dake mo'le, o se ife Olorun, o sun booli, o sise
f'Oluwa, oko pon fun ikore alagbase ko to o, mo 3. Aye nlo s'opin o, e je ka sin Oluwa bo ti ye, ijiya
gbo ti Jesu npe mi lohun rara pe, tani emi yo ran nbe lori awon alaigboran, aya Loti to s'aigboran
lo. Chrs:-Tani o/6x, yo lo o, tani o si .............Int o d'owon iyo, tete sa asala, ki o ma s'egbe.
Chr:-… Int
Solo:- Ore mura lati je ipe Oluwa
All:- Ore mura lati je ipe Oluwa 4. Jade kuro ninu iwa ese, jade kuro ninu iwa eeri
Solo:- Bi o ba je ipe re, a ba o se gbogbo, gba emi re la ninu ibinu Olorun o, ese
All:- Ore mura lati je ipe Oluwa aye ti p'apoju bii ti sodomu, Olorun ti setan lati
Solo:- Sise f'Oluwa, ki o gba ere repete be ile aye wo, tete sa asala ki o ma s'egbe m'aye
All:- Ore mura lati je ipe Oluwa o. Chr:-… Int
Solo:- Gbogbo isoro re yo so won d'alailagbara
All:- Ore mura lati je ipe Oluwa
10 7
Idupe
Victorious Power House, P. O. Box 1682, Isekolowo,
Ogo ni fun Olorun loke orun, Oba ti o fun wa Oyo, Oyo State, Nigeria.
ni gbogbo atilehin lori eto yii. Email: [email protected]
Phone no.: +2348022427210
8 9
Order of programme
Building Materials needed:
Programme Moderator - Pro. Oyedemi Raphael
Idupe
Victorious Power House, P. O. Box 1682, Isekolowo,
Ogo ni fun Olorun loke orun, Oba ti o fun wa Oyo, Oyo State, Nigeria.
ni gbogbo atilehin lori eto yii. Email: [email protected]
Phone no.: +2348022427210
Order of programme
Building Materials needed:
Programme Moderator - Pro. Oyedemi Raphael