Jump to content

Janez Drnovsek

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Janez Drnovšek
President of Slovenia
In office
22 December 2002 – 23 December 2007
Alákóso ÀgbàAnton Rop
Janez Janša
AsíwájúMilan Kučan
Arọ́pòDanilo Türk
Prime Minister of Slovenia
In office
17 November 2000 – 11 December 2002
ÀàrẹMilan Kučan
AsíwájúAndrej Bajuk
Arọ́pòAnton Rop
In office
14 May 1992 – 3 May 2000
ÀàrẹMilan Kučan
AsíwájúLojze Peterle
Arọ́pòAndrej Bajuk
President of Yugoslavia
In office
15 May 1989 – 15 May 1990
Alákóso ÀgbàAnte Marković
AsíwájúRaif Dizdarević
Arọ́pòBorisav Jović
Secretary General of the Non-Aligned Movement
In office
7 September 1989 – 15 May 1990
AsíwájúRobert Mugabe
Arọ́pòBorisav Jović
Àwọn àlàyé onítòhún
Ọjọ́ìbí(1950-05-17)17 Oṣù Kàrún 1950
Celje, Yugoslavia (now Slovenia)
Aláìsí23 February 2008(2008-02-23) (ọmọ ọdún 57)
Zaplana, Slovenia
Ẹgbẹ́ olóṣèlúMovement for Justice and Development (2006–2008)
Other political
affiliations
League of Communists (Before 1990)
Liberal Democracy (1990–2006)
(Àwọn) olólùfẹ́Majda Drnovšek (Divorced 1980)
Alma materUniversity of Ljubljana
University of Maribor

Janez Drnovsek (May 17, 1950 – February 23, 2008) A bí ní ọdún 1950. Ó jẹ́ olóòtú ìjọba Slovenia ní 1992 sí 2002. Lẹ́yìn èyí ni ó di àrẹ ilẹ̀ náà. Ní ọdún 1999 ni àìsàn kan ń bá a jà ní kíndìnrín. Ẹ̀kọ́ nípa ‘economics’ ni ó kà. Ó sì di ọmọ ilẹ́ asòfin ilẹ̀ slovenia ni ọdún 1986. Iṣẹ́ ribiribi ni ó ṣe láàrin ọdún mẹ́wàá tí ó fi ṣe olóòtú ìjọba. Ó jẹ́ kí ilẹ̀r eẹ̀ dara pọ̀ mọ́ European union àti NATO ní 2004. Oṣù kéjìlá ọdún 2007 bí ó fi ipò àrẹ ilẹ̀ slovenia sílẹ̀. Ó kú nígbà tí ó di ọmọ ọdún mẹ́tàdínlógọ́ta.