Jump to content

J. E. A. Wey

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
(Àtúnjúwe láti Joseph Edet Akinwale Wey)
Vice Admiral/Igbakeji Adarioko-ogunojuomi Joseph Edet Akinwale Wey
2nd Vice President of Nigeria
In office
July 29, 1966 – July 29, 1975
ÀàrẹYakubu Gowon
AsíwájúBabafemi Ogundipe
Arọ́pòOlusegun Obasanjo
Àwọn àlàyé onítòhún
Ọmọorílẹ̀-èdèNigerian
Ẹgbẹ́ olóṣèlúNone (military)

Joseph Edet Akinwale Wey (ojoalaisi 12 December 1990) [1] je omose ologun ojuomi orile-ede Naijiria to figba kan je, bi olori Ile-ise Ologun Ojuomi Naijiria,[2] adipo Alakoso Oro Okere,[3] ati Oga Gbogbo Omose Ologun ni Ibujoko Togajulo,[4] eyi to so di de facto Igbakeji Aare ile Naijiria nigba ijoba Yakubu Gowon. O fi tipatipa feyinti nigba ti Murtala Mohammed fitipagbajoba lowo Gowon.[4]


  1. "Nigerian Navy Golden Jubilee". Nigerian Navy. Retrieved 2007-07-06. 
  2. Siollun, Max. "Aburi: The “Sovereign National Conference” That Got Away". Gamji. Retrieved 2007-06-16. 
  3. "An Attentive Listener". Time. Time Warner. 1970-03-02. Archived from the original on 2010-10-30. Retrieved 2007-06-16. 
  4. 4.0 4.1 Mohammed, Murtala. "Murtala Muhammed's First Address to Nigeria". Nigeriavillagesquare.com. Nigerian Village Square. Retrieved 2007-06-16.