Jump to content

Pam Grier

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Pam Grier
Pam Grier at L6 convention, in 2009.
Ọjọ́ìbíPamela Suzette Grier
26 Oṣù Kàrún 1949 (1949-05-26) (ọmọ ọdún 75)
Winston-Salem, North Carolina, United States
Iṣẹ́osere
Ìgbà iṣẹ́1969–doni

Pamela Suzette "Pam" Grier (ojoibi May 26, 1949) je osere ara Amerika. O gbajumo ni ibere 1970, leyin to kopa ninu awon filmu blaxploitation bi Foxy Brown to se ni 1974.