Jump to content

Toyin Falola

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Toyin Falola
Ìbí1 January 1953
Ibadan, Nigeria
Ará ìlẹ̀Nigeria
Ọmọ orílẹ̀-èdèNigerian
Ẹ̀yàYoruba
PápáÌtàn Afrika
Ilé-ẹ̀kọ́University of Texas, Obafemi Awolowo University
Ó gbajúmọ̀ fúnHistoriography in Africa

Tòyìń Òmòyẹ́ńì Fálọ̀là ( á bì nì ọ̀jọ́ kìńì óṣù kiìńì ọ̀dùń 1953 nì ìlù Ibadan). Fálọ̀lá jẹ́ òlùkọ̀táń ọ̀mọ́ ìlẹ̀ Naijiria áti ọ̀jọ̀gbọ̀ń ńìńù ẹ́kọ̀ ìmọ̀ Aláwọ̀dùdù (Afrika). Lọ̀wọ̀lọ̀wọ̀, ò jẹ́ òlùdárí Jácọ̀b átì Frances Sange Monssiker chair ńìpá ìńù rere sì ènìyáń (Humanitarian) èyì tì ò wá nì ìlè -ẹ́kọ̀ gìgá yùńífásìtí Austìń tì ò wá nì ilu Texas. Fálọ̀lá gbá òyè akọ̀kọ́ ti yùńìfásítì (B.A). Ò tùń gbá òyé ìmọ̀ ìjìńlè (Ph.D) ńì ọ́dùń 1981 ńìńù íwé ítáń (History) Ni ílé-ẹ́kọ̀ gìgá yùńìfásítì tì Ọ̀báfẹ́mì tì òwá ńì ílè-ìfílè-òrìlẹ́dẹ̀ Ńáìjìríá. Fálọ̀lá ọ̀mọ̀ ẹ́gbẹ́ ájùmọ̀ṣé tì ò gá jùlọ̀ nìpá iwe itan átì tì ìlé-ẹ́kọ̀ gìgá nìpá ìwé kìkọ̀ sí ẹ́ńìyáń tì òrìlẹ́ èdé Ńáìjírìá . Ìwé tì ò kọ̀já ẹ́gbẹ́rùń káń ńì Fálọ̀lá tì kò titè .




Áwòń Íṣẹ̀ Ìkẹ́kọ̀ átí Áwọ̀ń Ámì Ẹ́yẹ̀

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Ìwádì tì Ọ̀jọ̀gbọ̀ń Tòyìń Fálọ̀lá ńì ifẹ̀ sì jù ńì ìtáń áláwọ̀ dùdù látì bì ọ̀dùń 19th cẹ́ńtùrì ńìpà tì ìṣẹ́ ìlẹ́ ékò tì ìlù Ìbádáń; awọ̀ń ágbégbé tì ò ńì ifẹ́ sì pẹ́lù ńì Afrìká, Látì Amérìká átì òrìlẹ́ édé Ámẹ́rìká. Lárá áwọ̀ń ékọ̀ tì Ọ̀jọ̀gbọ̀ń Fálọ̀lá tì kò ńì ìfíháń(Introduction) sì Íṣẹ́báyè (Traditional) Àfrìká, èyì tì á pìlẹ́ ṣé fùń awọ̀ń akẹ́kọ̀ Ni òríṣìrìṣí ìpìńlẹ́ ńìńù ẹ́kọ̀ imọ̀ Áfrìká. Ati èpìstòmòlọ̀gíẹ́s tì Áfrìká.

Fálọ̀lá bẹ́rẹ̀ íṣẹ́ òlùkọ̀ńì rẹ́ ńì Párì ọ̀dùń 1970. Ńìgbátì ó má fì dì ọ̀dùń 1981, Fálọ̀lá tì dì òlùkọ̀ńì ńì ìlè ẹ́kọ̀ gìgá yùńìfásìtí tì ò fìdí kálẹ́ sì ìlé ìfẹ́ ńi ìlẹ́ Ńáíjìríá. Ò daraọ̀ mọ̀ ẹ́ká íkọ̀wé tì òwá ńì yùńìfásítì tì Texas tí ó wá ńí Áùstìń ńì ọ̀dùń 1991. Ò tùń gbá ìṣẹ́ òlùkọ̀ álákọ̀kọ̀ díẹ́ ńì yùńífásítì tí Cámbrídgé nì òrìlè ede Eńgláńdì.

Ọ̀jọ̀gbọ̀ń Fálọ̀lá Ti gba ọ̀rìṣìrìṣì awọ̀ń aye ìbùyíńfùń Ti do ki ta Ati awọ̀ń Amin ẹ́yẹ̀ Ni órìṣìrìṣì agbegbe ni agbaye, lara wọ̀ń Ni ami ẹ́yẹ̀ Ti Lincolń, Amin ẹ́yẹ̀ Ti She iku Áńtá Diòp, Amin ẹ́yẹ̀ Ti Ámístád, Amin ẹ́yẹ̀ ti SIRAS fun ìráńlọ̀wọ̀ ti ò tá yò fùń ìkẹ̀kọ̀ Lori Áfrìká, ami ẹ́yẹ̀ fùń distinguished Africanist, ami ẹ́yẹ̀ Ti Je an Holloway ti ílé ẹ́kọ̀ gìgá fásìtì tì Texas tì ò wá ńì ìlù Austìń fùń òlùkọ̀ńì tì ò dárá jùlọ̀ tí chancellor's Council átì ámì ẹ́yẹ̀ tì táyò lò career Research. Fálọ̀lá tùń gbá hòńórárí ìyì tí dòkìtà lẹ́tá (doctors of letter) látí òwò ìlè ẹ́kọ̀ gìgá fásìtí tì ìkọ̀ṣẹ́ ọ́gbìń ńì ílù ábẹ́okùtá(FUNAAB) ńì ọ̀dùń 2018.


TOFAC

Ńì òrìlẹ́ édé Ńáìgírìá, ápèrò káń wá tì áwọ̀ń ákòjọ̀pọ̀ ẹ́gbẹ́ Ìbádàń Cultural Studies geohp sọ̀ ńì òrùkọ̀ Tòyìń Fálọ̀lá. Ọ̀jọ̀gbọ̀ń Ádémọ̀lá Dasylva ńì òlùdárì ákòjọ̀pọ̀ ẹ́gbẹ̀ yì. Ápérò tì á pé òrùkò rẹ́ ńì Tòyìń Fálọ̀lá International Conference on Africa átì Africa Diaspora (TOFAC) , ńì ò kọ̀kọ̀ wáyé ńì ìlù èkò ńìpásẹ́ Centre for Black African Arts átì Civilization+CBAAC),labè sò álákòsò ágbà, ọ̀jọ̀gbọ̀ń Tùńde Bábáwálé.