Àsìkò Ìwọòrùn Áfríkà
Ìrísí
(Àtúnjúwe láti West Africa Time)
black | UTC-1: Cape Verde Time. |
green | UTC: Western European Time · Greenwich Mean Time. |
blue | UTC+1: Central European Time · West Africa Time · Western European Summer Time. |
red | UTC+2: Eastern European Time · Central Africa Time · West Africa Summer Time · South Africa Standard Time. |
yellow | UTC+3: Eastern European Summer Time · East Africa Time. |
grey | UTC+4: Mauritius Time · Seychelles Time. |
Àsìkò Ìwọòrùn Áfríkà tí àwọn Gẹ̀ẹ́sì ń pè ní West Africa Time tí ìkékúrú rẹ̀ jẹ́ WAT, [1]ni akókò tí a ń ló ní agbègbè àárín gbùngbùn Ìwọ̀ Oòrùn ilẹ̀ Adúláwọ̀ bí ó tilẹ̀ jẹ́ wípé GMT) ni wọ́n ń ló ní orílẹ̀-èdè Benin tí òun náà wà ní inú ilẹ̀ Ìwọ̀ Oòrùn ilẹ̀ Adúláwọ̀. WAT yí fi wákàtí kan léwájú UTC (+1) , èyí jẹ́ kí ó ṣe déédé pẹ̀lú Central European Time. Púpọ̀ àwọn orílẹ̀-èdè ilẹ̀ Adúláwọ̀ tí wọ́n ń ṣamúlò UTC ni akókò an ma ń jẹ́ (UTC +0) .[2]
Àwọn orílẹ̀-èdè tí wọ́n ń lo UTC
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- Àlgéríà
- Àngólà
- Benin
- Kamẹrúùn
- Orílẹ̀-èdè Olómìnira Àrin Áfríkà
- Chad
- Orílẹ̀-èdè Olómìnira Olóṣèlú ilẹ̀ Kóngò
(western)
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |
Itokasi
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ "Time in West Africa". GMT - World Time & Converters. Retrieved 2022-10-20.
- ↑ "WAT". WorldTimeServer.com. 2016-01-08. Retrieved 2022-10-20.