Wikipedia:Àwọn Ìṣẹ̀lẹ̀ Bíi Ọjọ́ Òní/Ọjọ́ 1 Oṣù Kẹta
Ìrísí
Ọjọ́ 1 Oṣù Kẹta: Independence Day ni Bosnia and Herzegovina (1992)
- 1803 – Ohio di gbigba sodo bi ipinle Orile-ede Amerika 17k.
- 1961 – Uganda bere si ni sejoba ara re leyin idiboyan akoko.
Àwọn ọlọ́jọ́ìbí lóòní...
- 1889 – Watsuji Tetsuro, amoye ara Japan (al. 1960)
- 1914 – Ralph Ellison (fọ́tò), olùkọ̀wé ará Amẹ́ríkà (al. 1994)
- 1927 – Harry Belafonte, olórin àti òṣeré ará Amẹ́ríkà
Àwọn aláìsí lóòní...
- 1974 – Bobby Timmons, oni piano ara Amerika (The Jazz Messengers) (ib. 1935)
- 1995 – Georges J. F. Köhler, onimo biologi ara Jemani (ib. 1946)
- 2006 – Johnny Jackson, oniluu drum ara Amerika (The Jackson 5) (ib. 1951)