Jump to content

Wolfgang Pauli

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Wolfgang Pauli
ÌbíWolfgang Ernst Pauli
(1900-04-25)25 Oṣù Kẹrin 1900
Vienna, Austria-Hungary
Aláìsí15 December 1958(1958-12-15) (ọmọ ọdún 58)
Zürich, Switzerland
Ará ìlẹ̀Switzerland
Ọmọ orílẹ̀-èdèAustria
PápáPhysics
Ilé-ẹ̀kọ́University of Göttingen
University of Copenhagen
University of Hamburg
ETH Zürich
Princeton University
Ibi ẹ̀kọ́Ludwig-Maximilians University
Doctoral advisorArnold Sommerfeld
Other academic advisorsMax Born
Doctoral studentsNicholas Kemmer
Felix Villars
Other notable studentsSigurd Zienau
Ó gbajúmọ̀ fúnPauli exclusion principle
Pauli-Villars regularization
Pauli matrices
Pauli effect
Pauli equation
Pauli group
Coining 'not even wrong'
InfluencesErnst Mach
Carl Jung
InfluencedRalph Kronig
Àwọn ẹ̀bùn àyẹ́síLorentz Medal (1931)
Nobel Prize in Physics (1945)
Matteucci Medal (1956)
Max Planck Medal (1958)
Religious stanceRoman Catholic
Notes
His godfather was Ernst Mach. He is not to be confused with Wolfgang Paul, who Pauli called his 'real part.'

Wolfgang Ernst Pauli (April 25, 1900 – December 15, 1958) je ara orile-ede Ostria to je onimo fisiyiki oniriro ati ikan ninu awon asiwaju ninu fisiyiki ayosere. Ni odun 1945, leyin ti Albert Einstein ti filoruko re sile, o gba Ebun Nobel ninu Fisiyiki fun "afikun to se koko nipa iwari ofin tuntun Adaba re, opo iyasoto tabi opo Pauli," to jemo iro yiyi, to wa labe idimule elo ati gbogbo Kemistri.