Jump to content

The Return of Jenifa

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
The Return of Jenifa
AdaríMuhydeen Ayinde
Olùgbékalẹ̀Funke Akindele
Òǹkọ̀wéFunke Akindele
Àwọn òṣèréFunke Akindele
Denrele Edun
Rukky Sanda
Yinka Quadri
Helen Paul
Ireti Osayemi
Mercy Aigbe
Eldee
Ronke Ojo
Antar Laniyan
Tope Adebayo
Ìyàwòrán sinimáD.J. Tee
OlùpínOlasco Films and Records
Déètì àgbéjáde
  • 23 Oṣù Kẹ̀sán 2011 (2011-09-23)[1]
Àkókò172 minutes
Orílẹ̀-èdèNigeria
ÈdèYoruba, English

The Return of Jenifa jẹ́ fíìmù apanilẹ́rìn-ín ilẹ̀ Nàìjíríà ti ọdún 2011.[2] Funke Akindele ló ṣagbátẹrù fíìmù yìí, tó sì tún jẹ́ olú-ẹ̀dá-ìtàn nínú fíìmù yìí. Fíìmul yìí jẹ́ apá kẹta, tó tẹ̀lé Jenifa (2008). Olùdarí fíìmù yìí ni Muhydeen Ayinde.[3]

Àwọn ìtọ́kasí

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]